Gégé bí a ti mò wípé eré bóòlù ife àgbáyé ńlo lówó. Ahmed Musa tí Ó jé òkan Lára àwon omo agbábòòlú Nìjíríà ti gbá bóòlù méjì òtòtò wo ilé àwon alátakò won tí a mò sí ikò Iceland.

Tagged with: Àṣà Yorùbá