Home / Àṣà Oòduà / Àwòrán Obanikoro àti Oluremi Tinubu àti àwon omo egbé APC tó kùn ní ìlú èkó.

Àwòrán Obanikoro àti Oluremi Tinubu àti àwon omo egbé APC tó kùn ní ìlú èkó.

Photos Of Obanikoro With Oluremi Tinubu & Other APC Members In Lagos Today
Below are photos of Senator Obanikoro with Senator Oluremi Tinubu and others at 22nd edition of Lagos Central Senatorial District Town hall meeting.

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo