Home / Àṣà Oòduà / Èmi kò ní àrùn coronavirus – Yahaya Bello

Èmi kò ní àrùn coronavirus – Yahaya Bello

Gomina ipinle Kogi,Ogbeni Yahaya Bollo lo n forere lori ero ayelujara pe ki won se fi orokoro ko oun lorun, oun lo ni arun covid-19 gege bi awon oloselu Kan se n gbee kiri.


O ni loooto ni adari aabo ijoba apapo, Alagba Abba kyari to ni arun naa ba oun lalejo nigba ti o ti orileede Germany de.

O ni o wa ba oun kedun iku mama oun. O ni abewo naa ko muu dandan pe oun gbodo ko arun naa. O ni oun nikan ko ni ko ko arun naa lara re, Alhaji Lai Mohammed naa wa lara awon to fi abewo ye ohun si pelu awon eniyan pataki miiran.


Gomina tun wa ro awon oloselu ti won ko mo ju ki won ko owo je lo,o ni ko dara ki won fi arun coronavirus ko owo je rara. O ni asiko to ye ki iberu Olorun wa ju niyi. O ni oun ko si ni gba ki oloselu kankan lo oun lati ko owo je, eyi lo mu ki oun maa forere pe oun ko ni arun coronavirus rara.

About ayangalu

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.