Home / Àṣà Oòduà / Kí ni ojú ò rírí, kárí ká f’ojú fò lópò. Njé Eléhà ninèyí tàbí Egúngún?.

Kí ni ojú ò rírí, kárí ká f’ojú fò lópò. Njé Eléhà ninèyí tàbí Egúngún?.

Òrò náà só síni lénu ó tún buyò si, àbí bí èèyàn yóò bá jé òsákálá kí ó jé Òsákálá bí yóò sì jé Òsokolo kí ó ké Òsokolo, èwo ni òsákálásokolo. Èyí èèyàn sé Eléhà ni a ó pe eléyìí ni àbí Egúngún?. Eléyìí kojá òyé ti èmi.
Kí á ti è má fa òrò gún kò kúkú sí ìyàtò láàrin àwon méjèjì, èkú oko ni ìyàwó rè n wò kiri.

About Awo

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo