Aku ataro óò Adé kú ọjọ yìí Kíní orúkọ tí wọn npè Ìsọ yìí ní èdè ìlú ti’yin náà?????? #iya lájé
Ẹ jẹ́ kí á jọ kí GBajúmọ̀ Akọrin Jùjú nílẹ̀ yìí, Olóyè Ebenezer Obey Fabiyi kú ayẹyẹ oríkádún wọn ti ọdún kẹtàlélọ́gọ́rin (83) tó kò lónìí. Kí Olódùmarè ó fi àlàáfíà ṣe ẹ̀bùn Ogbó fún Bàbá
Iso lekuleja
Ìsọ̀ lékulẹ́ja tàbí Ìṣòro eléwé ọmọ.
Tapa tese
Iso alagbo, elewe tabi leku leja
Elewe omo