Obi ni bii Iku Obi ni bii Arun Obi ni nii Ofo Kolanut avert death Kolanut avert illness/disease Kolanut avert loss Obi(Kolanut) is sacred. He who bring Kolanut brings joy. Ase Ire O!!!
Read More »Iwure: Odu Okanransode
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Abu ise ana o a si tun ki orire iwonu ose tuntun, ose yi yio san wa si ire gbogbo ako ni to ona iparun lose yi o ase. Laaro yi mo maa fi ...
Read More »Igunuko !
Orunmila soro nipa ikin ifa !
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o a sin ku isimi opin ose, bi a se nwonu aye loni ako ni pare maye lara o ase. Laaro yi mo fe fi akoko yi fesi si ibeere awon ...
Read More »Orunmila Ni Olugbala Eda, Bee Naa Lo Si Tun Je Olugbala Fun Awon Irunmole Akegbe Re Naa
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Oni a san wa o, bi a se njade lo loni aanu eledumare koni fiwa sile o ase. Loni mofe ki e mo dajudaju wipe Orunmila ni olugbala eda, paapajulo awa adulawo bee naa ...
Read More »E gbo oro Olodumare ninu odu mimo ti Orunmila,
E jiire eyin eeyan mi, e je ki a gbo oro Olodumare ninu odu mimo ti Orunmila, mo nki lati inu Ogbe ‘gunda (Ogbeyonu ), o ki bayi pe,’ Bibi inu ko da nkan, suuru ni baba Iwa, agba to ...
Read More »Fi odu ifa mimo OTURUPONDI dupe oore lowo Olodumare
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku odun aku iyedun emin wa yio se pupo re laye ninu ola ati alaafia ara o ase. Mo se ni iwure laaro yi wipe gbogbo ohun ti a lelele lodun to koja lo ...
Read More »Ki Ni Oruko Eranko Yii
Ekale ooo!!! Kin ni oruko ti a n’pe iwu ilu yi ni ile Yoruba?
Gbogbo eyin apapo olorire lagbaiye mini ile nla I.K.O. NLA wayi o lawujo apapo awon ojogbon awo mimo Fun idanileko Lori ASA ile wa Opolo eni kokan wa koni di oku o Ifa koni kuru lakaye eni kokan wa o ...
Read More »Ejowo O Eyin Ojogbon!! Efun Wa Ni Imoran Lori Ala Yi O
Aki gbogbo eyin ojogbon awo mimo lagbaiye ninu ILE NLA I.K.O. nla wayi o Wipe :- (.KINNIHUN ORUNMILA.) Iye eni kokan wa koni ra ooo Ejowo ooo Ti obinrin basun tioba la ala wipe ohun pade were loju orun to ...
Read More »