Mariwo fi’bi faara la ile; Awo won ni Ile Ìlalà; A difa fun won ni Ile Ìlalà; Nibi ojumo rere tii mo ni; Ojumo rere lo mo wa loni o. Aase! Ifa says: Mariwo fi’bi faara la ile; The Awo ...
Read More »Odu Ifa Owonrin Meji
| | | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana, eledumare yio pese fun aini wa loni ase. Odu ifa OWONRIN MEJI lo gate laaro ...
Read More »Oríkì Ẹ̀rìn Òsun
Ẹ̀rìn moje ọmọ saaja, Ọmọ eléwé ladogba òróró maro, Ẹ̀rìn wagunwagun Ewá w’Ẹ̀rìn logun eniti yíò wá Ẹ̀rìn logun kowa àpò ide kolowa ọfà, Bàbá kòníbon ajíperin nílé, karo ń lè mọ wọn lójú ogun ẹni Ẹ̀rìn mọ jẹ́ ta ...
Read More »Ìfẹ́ láàárín ara wa
Ìfẹ́ láàrin ara wa Ìfẹ́ dára, Ìfẹ́ dùn bí a bá pàdé oní tí wá, Ìfẹ́ jẹ́ òhun tí ó má ń ṣẹlẹ̀ láàrin àwọn ènìyàn, Yálà ọkùnrin sí obìnrin, Obìnrin sí ọkùnrin, Ìyá sí ọmọ, Bàbá sí ọmọ, Ọkọ ...
Read More »Ìtẹ́lọ́rùn – #Ìtẹ́lọ́rùnṣepàtàkì.
Ìtẹ́lọ́rùn ni baba ìwà, Ìtẹ́lọ́rùn ṣe pàtàkì fọ́mọ adamọ, Ìtẹ́lọ́rùn ṣe kókó, A gbọdọ̀ ni ìtẹ́lọ́rùn, Kí a le rí ayé gbé, Kí a le gbáyé ìrọ̀rùn, Aìní ni ìtẹ́lọ́rùn le mú ni jalè, Bí ohun tí a ni kò ...
Read More »Aṣọ wíwọ̀
Èèyàn lèyí ni àbí wèrè? Asínwín lèyí ni àbí abugije? Ṣé aṣọ lèyí abi kini? Ha! Ayé tí bàjé, Gbogbo ọmọ adáríhunrun tí sọ àṣà nù, A gbé òmíràn, A fi aṣọ sílè láìwọ̀, A sọ ìhòòhò rí rìn di ...
Read More »Ìfẹ́ – Èyí wa fín àwọn olólùfẹ́ láti fi ranse sí olólùfẹ́ wọn
Ẹyín féràn ẹnu,ofi ṣe ilé, Irun féràn orí ,ofi ṣe ilé, Ìràwò òwúrò tèmi nìkan, Olólùfẹ́ mi, Nínú aba ayé yìí Ẹkuro emi mi alabaku ẹwa rẹ, Ọrọ ìfẹ́ yi n yimi Mo ni mi o nífẹ̀ẹ́ mon, Ife ìwọ ...
Read More »#Òmìnira
Òmìnira ṣe pàtàkì, Òmìnira ṣe koko fún gbogbo ohun Òlódùmarè dá, Bí ènìyàn bá nínú ìnira tàbí ìgbèkùn, Tí ó wá rí ìtúsílẹ̀, Àyípadà rere a dé, Ìfọ̀kàbalẹ̀ á wà, A bọ lọ́wọ́ ìdarí ọ̀gá, A bọ nínú wàhálà ...
Read More »Ogboni – Isese Lagba
EEPA MOLE !!!
Read More »ARUGBA is no longer a Virgin maid
Arugba is not only seen as a virgin maid any longer, she is regarded a goddess herself and people make prayers and cast all their problem on her as she bears the calabash and passes on to lead the people ...
Read More »