#Orisanla omoge onidodo
Read More »E wa wo ohun ti Ooni tun se nile ijosin
Ooni tuntun ti lo fori bale niwaju pastor fun esin awon alawo funfun, eyi to tunmosi jesu oga ogo nile ijosin. Awon kan ri gege bi ohun to ye fun eni to mo esin awon alawo funfun, sugbon awon kan ri gege ...
Read More »Awon oun marun-un te e mo nipa awon obirin
Se looto nii
Read More »Ori kini won gbe sinu obe yii?
E woju obe ke e muyan. Iyan ‘re obe e re!
Read More »Ki lo gbayi bi aso ibile wa?
Aso to fi iwa omoluabi han to si rewa loju; aso to ponni le, aso tomo le jogun lowo eni. Ninu maaki mewaa (10), meloo le fe fun baba atomo re nipa imura won?
Read More »Foto: Kini obirin le se na ?
Kini obirin le se na, to le mu oko re na bi eleyii pelu oyun ninu? Iru iwa awon odaju okunrin bayii bani lokan je gidi. Sebi o se maa ri lo ni yii?
Read More »Kini oruko awon osere yii?
Inu fiimu wo ni foto yii ti jade?
Read More »Alaafin Lamidi gbalejo Owa Obokun nilu Oyo
Oba Lamidi Adeyemi III, Alaafin tilu Oyo gbalejo Oba (Dr.) Adekunle Aromolaran, Owa tilu Ilesa ni aafin tilu Oyo
Read More »Sambo Dasuki wo gau! Falana setan lati gbe lo si ilejo idaran ti okeere
Agba ninu ise amofin to tun je agbejoro ti n ja fun eto omoniyan, Ogbeni Femi Falana ti seleri lati gbe oludamoran nipa eto abo fun ijoba apapo tele ri, Sambo Dasuki ati awon akegbe re ti won ka modi ...
Read More »Obatala & His Kettle Drum !
Igbin Drums are the sacred Drums of Obatala The broken poison box The broken sword Ifa divination was performed for Mobikugbe Mother of hare (Ehoro) Oriṣaala, lover of song and drum Also an elder among all oriṣas He has a ...
Read More »