Home / Author Archives: oodua (page 43)
Esu lalu okiri oko okiri ! (police of the universe)
Esu lalu okiri oko okiri ogo(police of the universe) ako ebo ti ofi orita se afin.Laroye ebora ti ron oju mo omo kinkankinkan. Esu mase mi omo elomi ni kose……….n.
Read More »Oriki Olodumare !
Olubabi Ifaniyi Power
Read More »Oro kan fun odaju abiyamo !
Eku ojumo esinku isimi oni,besini esin tun ku oro ilu, hmm awon yoruba ama paalowe wipe eniyo npanu eni ebinpanranku,Ewo omo tuntun jojolo yi nibi ti wonsonu si ninu poli bagi,sugbon osemilanu wipe omo natidagbere faye bayi ni oni paanu ...
Read More »E ba mi fun won loruko kan
Oruko Woni Kokoro yi nje ni Ile Yoruba ?
Eledumare iba re loni o…
Eledumare iba re loni o,akoda aiye iba,aseda aiye iba,baba mi odetunde iba re loni o,iya mi iba re,iba oluwo ,iba iya nifa,iba olojo oni, aku ose ogun o,ogun yio bawa se o,ao ni tele lodi,ogun yio la ona fun wa ...
Read More »Kini A ti npe Iru Awon Obirin Bayi ni Ile Yoruba ?
Awon èyà Yorùbá wo lo ma n ko irú Ilà yìí?
Awon èyà Yorùbá wo lo ma n ko irú Ilà yìí?
Read More »