Home / Blog Pagepage 76

Blog Page

Oga Bello àti iyalode Binta Mogaji

Awon agba osere apanilerin meji

Read More »

Ìyàwó mi dára sùgbón kò n’ìfé ìbálòpò léyìn ìgbeyàwó.

Ìyàwó mi dáa tí mo sì le pè ní aya rere sùgbón kìí gbà kí á bá ara wa lò nígbà tí ó ye, lóòtó aní omo okùnrin pèlú obìnrin. E jò ó kí ni mo le se? Mo ti ...

Read More »

Kílódé tí àwon omoge fi n’ìfé àwon tí ó ti n’íyàwó.

E jòwó mo fé kí e dá mi lóhùn dáadáa. Gbogbo àwon Òré mi tí ó ti n’íyàwó n’ílé ni òpò obìnrin ń súré tè lé, tí ó sì jé wípé àwon àpón bí ti àwa yí obìnrin díè ni ...

Read More »

Odu ifa IROSUN OSE/ALAJE

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isinmi ana o, Olorun eledumare yio jeki aje fi ile wa se ibugbe loni o ase. Odu ifa IROSUN OSE/ALAJE lo gate laaro yi, ifa yi fore aje lopolopo fun akapo ti o ...

Read More »

Musa Musa, olóòpá tí ó fó ilé Jonathan.

Àwon Agbófinró ti rí àwòrán olóòpá kan tí ó jé atónà fún àwon ìgárá olóshà tí ó fó ilé Ààre télè Goodluck Jonathan ní Gwarimpa Abuja. Musa tí a gbé lo sí ilé-ejó gíga díè (magistrate) ní ojó ìségun tí ...

Read More »

Omokùnrin kan tí orúko rè ńjé Charlyboy subú lulè nígbà tí won ń se àtakò Buhari. 

 Àmóhùnmáwòrán Channels ti pín fídíò tí ó se àfihàn omokùnrin kan tí ó ń jé Charlyboy nígbà tí ó subú lulè nígbà tí won ń tako Buhari lówó ní ìlú Abuja láàárò òní. Àwon Agbófinró fín tajútajú àti omi láti tú ...

Read More »

Òrékùnrin mi ń bínú sími.

E jòwó, mo fé àmòràn lórí ohun tí ó ye kí n se, osù kewàá rèé tí mo ti mo Òrékùnrin mi, a sì ní ìfé ara wa, sùgbón Òrébìnrin rè télè sì ń dàá láàmú, èyí sì ń jé ...

Read More »

Eré odún Òrìshà ní orílè èdè UK Edinburgh Fringe.

Àwon Òrìshà, Yemoja, Oya, Òshun, Elégba àti òshóòsì jé àwon Òrìshà tí ó dúró fún èdá ènìyàn ní gbogbo ònà, tí won sì máa ń wá sí ayé gbangba. Nígbà tí akoni wa òshóòsì, tí ó jé ògbójú ode, tí ...

Read More »

Olùkó kan ní Benue ni won ní kí ó San mílíònù kan àti ààbò Náírà (₦1.5m) fún owó orí.

Arákùnrin tí ó sèsè parí èkó, tí ó sì ń sisé olùkó ní ilé-ìwé aládàáni girama kan tí ó fé fé ìyàwó ní àwùjo kan ní Zone “A” ní ilè Tiv ní ìpínlè Benue, ni won ti fún ní àwon ...

Read More »

Àwon ènìyàn Nàìjíríà ní orí èro ayára-bí-àsá so pé kí won fún Cynthia Chinecherem ní egbèrún lónà lónà aárùndínlógbòn lé ní èédégbèta náírà

Àwon ènìyàn Nàìjíríà ní orí èro ayára-bí-àsá so pé kí won fún Cynthia Chinecherem ní egbèrún lónà lónà aárùndínlógbòn lé ní èédégbèta náírà (#525k) fún níní àmì “A” mésàn-án (9A1) nínú èsì ìdánwò àsekágbá girama. Rántí Cynthia Chinecherem, Arábìnrin tí ...

Read More »