Home / Blog Pagepage 95

Blog Page

Awon ona wo ni a le gba lati gba ara wa si ‘le ni oko eru paapa ni owo awon oyinbo ati arabu?

English: What are the ways to free ourselves from the physical, mental and spiritual enslavement especially from the hands of Europeans and Arabs?   Cc – Omo Oba

Read More »

Odu Eji Ogbe

Ìpẹpẹrẹ ìmọ ni farabalẹ ni jogunda Adia fun Orunmila Ifa nlọ ba wọn mulẹ budo Nita Iku nita Arun, Nita Ajogun Mẹrẹrindilogun Te nbẹ lode oṣalaiye. Slender-Palm-Frond-is-Patient-In-Taking-Its-Revenge Revealed the way to Orunmila when he was looking for a place to ...

Read More »

Ará Ọ̀run

Cc – Moyo Okediji

Read More »

Ifa naa ki bayi wipe…

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin ku isimi opin ose, eledumare yio saanu wa o ao ri tiwa se loni, iyan jija koni ranwa lo sibiti ako fe o ase. Odu ifa ogbeweyin ni ...

Read More »

Odo Iwoyi: Oro Kan Ni Nrumi Loju Ti Mo Si Nilo Amoran Lori Re.

E ku ile ni a n k’ara ile, e ku abo ni a n k’ero ona, ti a ba ti rira eni tipe, e ku atijo ni a ma nki ara eni. Mo ki gbogbo ebi Omo Yoruba Atata pata ...

Read More »

Ifa Toni Ki Bayi Wipe

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, oni a san wa o, eledumare yio gbo ohun ebe adura wa o ase. Ifa toni ki bayi wipe: Orunmila ni ori a lana kan Moni ori a lana kan ...

Read More »

Oju-Abe: Aare Mohammodu Buhari pase fun oga Agba Olopaa

Aare ile wa Nigeria, #Aare_Mohammodu_Buhari ti pase fun oga Agba yan-an-yan fun awon Olopaa nile wa lati tenu bo iwadii lori awon Ajo tiwon da sile lati maa pese Ounje ati Ohun-eelo fun awon Eeyan ti Iko-Onilakaadi-Ajajangbila #BOKOHARAM tiso di ...

Read More »

Omo Oodua Rere Nkan Semi Ose Idile Mi Pelu Nkan…

Omo oodua rere nkan semi ose idile mi pelu nkan lani ki majesi o ti oju obie re orun ara ma bo egbon mi jade laye ni ijeta ojo kinni osu kesan loju iyawa ha ha ha o ma se o ...

Read More »

Kini itumo asanya oro yi

Kilo ri lobe??? (A) TOFI GAARU OWO. (B) TOFI WARU SOWO.

Read More »

Today’s Sermon – (Ijo Orunmila Ato) inc, Taken From Ejiogbe

My sermon today, Sat.3rd Sept. 2016 at our House of Worship, Indigene Faith of Africa( Ijo Orunmila Ato)Inc, taken from Ejiogbe:-   Akole/ Theme Iwa onikaluku la o fi da l’ejo By their characters shall they be judged Isepe werewere ...

Read More »