Àwon àjo tí ó n mójú tó ètò ìdìbó tí a mò sí INEC ti kéde Gboyega Oyetola gégé bí eni tí ó gbégbà orókè níbi ìdìbò tí won tún dì ní àná. Omo egbé oní ìgbálè tí won fà ...
Read More »Òrò ìsítí gbó òréëwa?
Òrò ìsítí gbó òréëwa? -O féékú wàákú, Ìwõ ò fèékú wàákú sugbon kini kan lèmi fë kio mø daju, Sé nigba tó o wásí ile-aye sé kii sepé àrà(Wonder) ku mó ë ninu. Àrà tóò gbéwá silé ayé tóò ló, ...
Read More »E ku Ose Sango
Igba ara lanbura enikan kinbu sango lerun adifafun olukoso laalu arabambi Omo arigba ota Segun onbelarin ota onfi ojo jumo konminu ajogun…Tani Peri oba to oo Emi oo operire alade..Sango yiobawa Segun gbogbo Otawa aori tiwase.E ku ose sango, Ase ...
Read More »Òtúrá Òfún (Òtúráfùnún)
Àkúsàba Àyàndà Awo ilé Olúmẹ̀ri Àápáálá Ọmọ ilé san wón ó joko lọ Níjọ́ tí ń ṣọ̀gbọ̀gbọ̀ àrùn Tí ń najú aláì le dìde Olúmẹ̀ri Àápáálá làrùn ń ṣe Òún wá á le gbádùn gbogbo nǹkan òun lójú ayé òun ...
Read More »Àwòrán ará ilé Bbnaija télè tí a mò sí Alex, ìyá rè àti ìyá ìyá rè.
Àwòrán ará ilé Bbnaija télè tí a mò sí Alex, ìyá rè àti ìyá ìyá rè. Alex Asogwa pín àwòrán rè tí ó rewà àti ti ìyá rè àti ìyá ìyá rè tí ó rewà, ìran méta tí ó rewà ...
Read More »Omokùnrin odún métàlá (13) ni àwon olópàá ti mú látàrí ìbèrú tí ó ní sí won.
Omokúnrin kékeré kan ní won ti mó’ lé ní àgó olópàá látàrí ìbèrù tí ó ní fún àwon olópàá. Gégé bí ìròyìn se so, omokùnrin odún métàlá, tí ó sí jé olórí okúnrin ilé-èkó won, ni ó n pon omi ...
Read More »Tiwa Savage kúnlè kí ògá Shínà peter
Obìnrin àkókó ní inú egbé Marvin kúnlè wò ní orí ìkúnlè nígbà tí ó kí ògà gun àti ògbóntàgirigì tí a mò sí Shina Peter nígbà tí won n sí ilé-isé pefume brand, Sappire Scent ní Lenox mall ní ìpínlè ...
Read More »Bukola Saraki lo kí Ademola Adeleke ní ìpínlè Osun ní àná.
Bukola Saraki lo kí Ademola Adeleke ní ìpínlè Osun ní àná. Ààre ilé ìgbìmò Asòfin tí a mò sí Dókítà Abubakar Bukola Saraki ní àná tí lo kí omo egbé oní àbùradà tí a mò sí egbé PDP, èyí tí ...
Read More »Àwòrán kí ó tó di onó ìgbéyàwó ti olópàá kan àti olùwòsàn.
Gégé se gégé, onígègè tó pàdé asòpá ni òr olópàá àti olùwòsàn yí jé, bí olópàá bá kojú dogun tí ó sì pa lára, olùwòsàn tí ó jé ìyàwó rè yóò sì ba wò ó sàn . Àwòrán ti aya ...
Read More »Ọmùtí Gbàgbé Ìṣẹ́ (Ìrònú Ọlọtí)
Ilé ọlọ́ti ni ilé ìtura, ibẹ̀ ni àwọn ọ̀rẹ́ ti npàdé fàájì Ibẹ̀ náà ni àwọn èké, àti ọ̀dàlẹ̀ tin pàdé ara wọn Ti ọti bá wọra tán, ara a sì rọ̀ wọ́n pẹ̀sẹ̀, Ìgbéraga á wá wọ̀ wọ́n lẹ́wù ...
Read More »