Gégé bí a ti mò wípé òní tí ó jé Ojó Àbáméta ni ìpínlè Osun yóò dìbó fún ènìyàn tí won fé kí ó di aláse lórí won. Egbé kòòkan sì ti fi omo egbé sílè . Gboyega Oyetola ni ...
Read More »Gómìnà Arégbésolá fún àwon olùkó ní èbùn okò àti àwon èbùn míràn.
Gómìnà ìpínlè Osun tí a mò sí Rauf Aregbesola lo sí àjo àwon ilé-èkó àwon alákóbèrè pèlú àwon adarí míràn tí won péjú sìbè láti pín okò fún àwon òsìsé. Kìí se okò níkan ni ó fún won o bí ...
Read More »Àwon arákúnrin méjì kan jà lórí eni tí yóò jókòó sí iwájú okò.
Àwon èrò méjì ni a rí lónìí tí won n jà látàrí eni tí yóò jóko sí iwájú oko ní Èkó . Nígbà tí ó yá ni awakò ti awon méjèèjì jábó látàrí bí won se n se bí eni ...
Read More »Arákùnrin kan ni ó kú sínú odò nígbà tí ó sòrò nípa èmí òkúnkún.
Arákùnrin tí ó n gbé ní Èkó ni ó kú nígbà tí ó lo kí ègbón rè ní Ujeme, Ekpoma, ìpínlè Edo, ní won ti rí òkú rè nínú odò ní ilé rè, léyìn tí a gbó wípé ó sonù. ...
Read More »Linda Ikeji padà so orúko baba omo rè, ó wípé Sholaye Jeremi ni baba omo òun àti oko tí n bò lónà.
Elétí Ofe, Linda Ikeji ti padà so baba omo rè, ó sì ti so wípé Sholaye Jeremi ni baba omo òun . Ó tún so wípé orúko omo òun ni Jayce Jeremi , ó ko síbè wípé… ” mò n ...
Read More »Davido, Gbajúgbajà olórin tí ó tún jé omo ebí Adeleke wo agbádá tí àwon egbé oní Àsìá se tí won sì ko orúko egbé won si.
Olórin, tí ó tún jé òtòkùlú ti n se isé takuntakun láti ri dájú wípé, sínétò Ademola Adeleke di Gómìnà ìpínlè Òsun ní ibi ìdìbò tí ó n bò ní ojó àbáméta yí. Ó tí è ti n sisé takuntakun ...
Read More »Akékòó tí ó se dáradára jùlo ní ilé-èkó gíga tí a mò sí ABUAD gba èbùn nlá fúm oríre yí.
Bí omo eni bá dára kí á wí, Akékòó gboyè ti ìmò tí ó n se ìtòjú ènìyàn tí a mò sí Medical Student, ti gba èbùn pàtàkí tí a mò dí Okò bògìnì àti owó goboi. Esther Azom ni ...
Read More »Gbajúgbajà elétíofe, tí a mò sí Linda Ikeji ti bí omo okùnrin làntì lanti
Gbajúgbajà a gbé òrò sórí aféfé ti gbe sí orí èro ayélujára tí a mò sí insitagiramu, láti jé kí gbogbo àgbáyé mò wípé òun ti bímo, nígbà tí ô ya àwòrán n’ílé ìwòsàn, tí ó sì pe omo máà ...
Read More »Iba Gani Adams pàdánù baba rè .
Baba Ààre Ona-kakanfo ti ilè Yorùbá tí a mò sí Iba Gani Adams ti lo. Pa Lamidi Adams tí ó ta téru nípà ní ojó Àbáméta ní ilé ìwòsàn aládáni ní ìpínlè Eko, baba kú ní ìgbà tí won fé ...
Read More »Asòfin egbé APC, tí a mò sí Hon. Timothy Owoeye, fi èjè wè ní òrú gànjó.
Owó pálábá Asòfin egbé APC tí ó sì jé gbòógì , tí ó sì jé asojú ilé ìgbìmò asòfin tí Ilésà ní ìpínlè Osun, ni owó bá nígbà tí ó n fi èjè wè ní àrin òru tí ó sì ...
Read More »