Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Idile Alayo wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose yi. ...
Read More »Ounje UNJE Eme Fun T’ooro Yii – 26.05.2016
HUN ! B’o ti wu ki a pe laye to … A pee lorun ju bee lo… :::: WOO ORE WA ! #Igba o lo bi #Orere.. Bee, #Laye taa wa yii ko lo bi #Opa_ibon ::::::: DAKUN ORE WA ...
Read More »Odo Iwoyi – 2
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Odo Iwoyi wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose yi. ...
Read More »Eeto Owe L’esin Oro – 3
A ku deede asiko yii o ni aafin ilumoye, moki gbogbo wa kaabo si akotun eeto yin, eeto wa OWE L’ESIN ORO, oro l’esin owe ti oro ba sonu owe ni a o fi waa jade. Ope nla lo si ...
Read More »Lori Eto Tonii: Kini nje Ela ?
* Kin ni nje ELA ? Abi Taani #ELA je gan-an ? * Nje ESIN ati #ASA Yoruba tako ara won bi ? * Bawo ni # Ela_boru , Ela Boye , Ela bo sise se je Ede ikini fun ...
Read More »See where to buy Items like Opon Ifa, Books, African Fabric, Orisa beads and others
Look no farther for your African Spiritual Items like Opon Ifa, Books, African Fabric, Art works, Orisa beads, Traditional Songs, Brass items, Kolanut, Spiritual Item…Ancestral Vision presents…..all at affordable prices…IRE O!!! Ifa staff(Iroke Ifa) and Ifa divination tray(Opon Ifa) at ...
Read More »Eeto Owe L’esin Oro
A ku deede asiko yii o gbogbo olugbe aafin ilumoye, eeto yin eeto wa owe l’esin oro ni o tun wole de weere yi ooo, e wa nkan fidile ki a dijo gbadun eeto ti toni. Siwaju ki eeto o ...
Read More »Eto Olobe Loloko: Sokoyokoto !
Adupe lowo eledua, oba alaanu, olorun to ohunkohun ko sooro se fun lati se,Adupe lowo olorun ti o tun ka wa ye ni ojo toni, a ki gbogbo wa ku bi oju ojo ti ri oo, nigiriya a kuku de’run ...
Read More »‘Yee! Yee!! Ni gbogbo n ke’
Basẹ ba mumi Omi a tan ninu asẹ, Bígèrè ba mumi Omi a tan ninu ìgèrè, ko tan ko tan lajá á lami; Ó tán n bí ò tàn? A ráta, a rata, ata kan ojú, ata n tani bi ...
Read More »Gbolun kan fun baba oni bata yi
Eku dede asiko yi ooooo. E jo eyin omo ilu mi
Read More »