E MAA WI TELE MI : ……… *Osu karun-un yii, osu ire owo ni fun mi. *Osu ire ile kiko ni fun mi. *Osu ti maa ra oko ayokele. *Osu igbega lenu ise mi ni. *Osu idunnu ni yoo je ...
Read More »Ibeere Toni
Egbo eyin o ogbon,…nje oda ki Iyawo ile o mo ko orun fun okore ? ….tabi ki oko naa o ko fun Iyawo re?……. Iru nkan wonyi se o ma ndin Ife Ku ni abi oma tubo mufe gbile si???????????
Read More »Oko mi ati iya re loba aye mi je
Akole oke yi lo se apejuwe oro arabinrin kan , eyi to fi esun kan iya oko re wipe o gba arisiki oun fun omo (oko re) Nigbati obinrin yi so oro , emi bi leere wipe SE OKO SAA ...
Read More »Iwure Owuro Ipari Osu
E MAA WI TELE MI : ….. *Airije-airimu nile aye mi ti dopin. *Ibanuje ninu aye mi ti dopin. *Ijakule ninu aye mi ti dopin. *Ise mi ko ni dojuru *Ogun aye ko ni borii mi. *Oju owo ko ni ...
Read More »Fi ere si temi Eledumare
Ojulu! ojo nan re bi anan sugbon o ti pe odun kan bayi Eledua modupe, ibi ti ore nan de duro maje ko taku sibe o, fi ere si temi Eledumare, MAJE KIN KAABAMO BO TI WU KORI, orewa toripe ...
Read More »Orewa Abi Iwonan Ti Gbagbe Ile !
Orewa abi iwonan ti gbagbe ile, toripe eniyan to so ile nu ti so apo ‘ya ko, ajo ko dabi ile lo d’ifa fun agiliti to pada wa tun ile-baba re se, se ki se pe o ti gbagbe orirun ...
Read More »Oba Erediauwa Ti Waja
Ojulu ooooo! iku ti pa abiri abiri ti rorun alakeji oooo! iku ti pa okan lara awon omo ODUDUWA Oba-Benin, gbogbo eyin ojulowo omoYORUBAatata e ku araferaku eni re OBA-EREDIAUWA ti ile-benin. bo ba de orun ko se orun re. ...
Read More »Awon osu ni ede Yoruba (12 Months of the Year in Yoruba Language)
E bami kaa si eti awon omo ni ile, January – seere February- Irele March – Erena April – Igbe May – Ebibi June -Okudu July – Agemo August – Ogun September -Owewe October – Owawa November – Beelu December -Ope.
Read More »YORÙBÁ DÙÚN KÀÁÁÁ
A – Alaafia ni fun o. B – Buburu kan ki yo o subu lu o. D – Dugbedugbe ibanuje ko ni ja le o l’ori. E – Ebi o ni pa o nibi ti odun yi ku si. E ...
Read More »Talo ma pani lerin julo ninu awon won yi?
Ebeere Toni: Talo ma pani lerin julo ninu awon won yi?
Read More »