Home / Iroyin Pajawiri (page 33)

Iroyin Pajawiri

KÍ LÓ BÀJẸ́ LÉDÈ WA

Ẹ jẹ́ kí a tibi pẹlẹbẹ mú ọ̀lẹ̀lẹ̀ jẹ. N jẹ́ fífi gẹ̀ẹ́sì kọ́ni lédè Yorùbá le múni yege dáada nínú ẹ̀kọ́ èdè Yorùbá bí? Gẹ́gẹ́ bíi òwe gẹ̀ẹ́sì kan tí ó wí pé, “the best way to understand a ...

Read More »

Odún pé, odún jo, àmòdún wa èsín pé.

Ikú bàbá yèyé, Aláse èkejì Òrìsà, baba wa Aláàfin ti ilè Òyò, Oba Lamidi Adeyemi 111 se ayeye ojó ìbí rè ní òní tí won pé ogórin odún (80). Àrà méèrírí ni kábíèsí, Ikú bàbá yèyé nítorí baba ni wón ...

Read More »

Ikún je dòdò ikún n rédìí, Ikún kò mò pé ohun tí ó dùn a máa pa ni.Arábìnrin yí ni ó gba orí ìbùsún ya wèrè.

Ìròyìn jé kí á mò wípé arábìnrin yí ya wèrè léyìn tí eni tí ó ti láya nílé ba lájosepò tán. Gégé bí eni tí ó sún mo se so. Ó so wípé ó ti mo omobìnrin yí lára kí ...

Read More »

Isé kìí pa ni, ayò ní pa omo ènìyàn

Arábìnrin kan ni aso rè fàya ní enu ìdí látàrí àsejú rè nípa ijó tí ó fé kó mólè dáadáa, kí ó tún owó ijó náà mú láti ilè. Nínú fídíò tí a rí wò, tí a ti yo àwòrán ...

Read More »

Òkan lára Ilé ìgbé àwon akékòó ti Ilé-èkó gíga ifáfitì ti ìlú ilé-ifè tí a mò sí Obafemi Awolowo University gbiná lánàá.

Òkan lára ilé ìgbé àwon Akékòó ti ilé-èkó gíga ifafitì ti Obafemi Awolowo gbiná ní alé àná. Ilé ìgbé yìí a máa jé Alumni hostel, bí ó ti lè je wípé a kò fi tara tara mo bí ó se ...

Read More »

Bàbá Sàlá òrun rere re o. Gbajúgbajà elérí orí ìtàgé, tí gbogbo èèyàn mò sí bàbá Sàlá ti gba òrun lo ní àná ojó kesàn-án osù kèwà odún tí a wà yí.

Tí won bá ni èèyàn apanilérìn ni baba won kò paró rárá, nítorí àwon gangan ni oyè adérìn-ín-p’òsónú ye. Moses Olaiya Adejuwon (M.O.N), lórúko baba súgbón bàbá Sala ti gba orúko lówó won. Àsé kò sí eni tí kò ní ...

Read More »

Ìyá omo keta gbajúgbajà olórin tí a mò sí Wizkid, tí orúko ìyà omo náà a máa jé Jada Pollock pín àwòrán omo rè, Zion.

Ìyá omo keta gbajúgbajà olórin tí a mò sí Wizkid, tí orúko ìyà omo náà a máa jé Jada Pollock pín àwòrán omo rè, Zion. Alámójútó Olórin àgbáyé, Wizkid tí ó padà di ìyá omo rè, Jada Pollock pín àwòrán ...

Read More »

Linda Ikeji àti omo rè, tí orúko omo náà n jé Jayce Jeremi nínú àwòrán tuntun.

Gbajúgbajà elétíofe tí gbogbo ayé mò sí Linda Ikeji tí ó sèsè bí omo okúnrin rè ní ojó ketàdínlógún osú kesàn-án odún tí a wà yí, pín àwòrán sí orí èro insítágírámù pèlú omo rè, Jayce. Ó ko síbè wípé… ...

Read More »

Ibon !

Read More »

Ògúndá Ọ̀wọ́nrín (Ògúndẹ̀rín)

Àtẹ́lẹwọ́ mi ọ̀tún ni mo fi kọ́’fá ń dídá Mo mọ Ifá ń dídá A dífá fún Akítán tíí ṣe ọmọ’yè Oníkàá Àtẹ́lẹwọ́ mi òsì ni mo fi kọ́bò ní gbígbà Mo mọ ìbò ni gbígbà Dífá fá fún Aṣọ̀gbà ...

Read More »