Home / Demo Blog With Mappage 89

Demo Blog With Map

Ki Ni Oruko Eranko Yii

Read More »

Ekale ooo!!! Kin ni oruko ti a n’pe iwu ilu yi ni ile Yoruba?

Gbogbo eyin apapo olorire lagbaiye mini ile nla I.K.O. NLA wayi o lawujo apapo awon ojogbon awo mimo Fun idanileko Lori ASA ile wa Opolo eni kokan wa koni di oku o Ifa koni kuru lakaye eni kokan wa o ...

Read More »

Ejowo O Eyin Ojogbon!! Efun Wa Ni Imoran Lori Ala Yi O

Aki gbogbo eyin ojogbon awo mimo lagbaiye ninu ILE NLA I.K.O. nla wayi o Wipe :- (.KINNIHUN ORUNMILA.) Iye eni kokan wa koni ra ooo Ejowo ooo Ti obinrin basun tioba la ala wipe ohun pade were loju orun to ...

Read More »

Iwure Ojo Eti

Moki gbogbo ojogbon awo mimo lagbaiye ninu ile nla wayi o Wipe :- (.KINNIHUN ORUNMILA OO.) (.Ilosiwaju Ishese Lo Jemi Lo Gun o.) Mofi asikoyi gba ni iwure fun gbogbo eda omo adariwuhun tioba lefi atejishe ee se (Aseee) labee ...

Read More »

Ifa olokun adore dayo aso oro gbogbo wa di ayo ooo.

Ase !

Read More »

Odo Iwoyi – E Gbo Bi Atejise Toni Ti Lo

Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wi pe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Odo Iwoyi wi pe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ...

Read More »

Isebo ni isegun baa ti waye pa a ri, la a

ri ………Ohun gbogbo lowo ori eni. Ori mi ma pada leyin mi. Ojumo Ire o!

Read More »

Ose tu’a

ko-mi-koro awo Ewi l’Addo Orun koko-ko awo Ijesa m’Okun Alakan nigbo ‘do t’eye ifá kerekere-kere adi’a fun Igba Irunmole ajikotun obu okan fun Igba Imole ajikosi alukin fun Orunmila nijo ti won ti Isalu orun bo wa Isalu aiye Eledumare ...

Read More »

APINTANBI

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a si tun Ku isimi opin ose eledumare koni jeki a fi eleyi se asemo o ase. Laaro yi mo fe so die nipa oro APINTANBI ti awon opuro ati ...

Read More »

Isu Oro bale ro pee…

A da fun eji, ti o ma bowo fun iko Odidere, won ni ko kara nile, Ebo ni ko mu se. Ojo o ni ro ko pa ina iko Odidere, Iko Odidere d’Orisa. Ni Agbara Olodumare ati oruko Orunmila, Gbogbo ...

Read More »