Yannick Arnauld Engolo láti orílè èdè Cameroon tí ó sì jé ènìyàn Swiss tí ó dá Miscas àti priceless corporation sílè ni a ti fi èsùn kàn látàrí wípé ó pa àwon omo rè méta. Ó ti è pe ...
Read More »Àwon omo egbé òkùnkùn Eiye àti Àíye ti kéde wípé àwon kò se mó.
Àwon omo egbé òkùnkùn Eiye àti Àíyè ti so wípé àwon kò se mó nígbà tí won se ìwóde gbangba ní ìpínlè Èkó.
Read More »Mikel Obi fi àyè sílè bá àwon omo rè obìnrin méjì Ava àti Mia seré.
Olga, ìyàwó ògbóntàrigì agbá bóòlù Mikel Obi, pín àwòrán ara rè nígbà tí ó n bá àwon omo rè seré , tí ó sì n ka ìwé fún won .
Read More »Bukola Saraki pàdé Akòwé Ìjoba gbogbogbò tuntun Boss Mustapha.
Ààre ilé-ìgbìmò asòfin Bukola Saraki pàdé Akòwé ìjoba gbogbogbò tuntun (SGF)Boss Mustapha.
Read More »Ambode wo okò ojú omi láti rin ìrìn àjò lórí omi .
Dr. Akinwumi Ambode, Gómìnà ìpínlè Èkó se ayeye láti we okò ojú omi tí ó sèsè rà, okò ojú omi náà sì wà fún ìpínlè Èkó, bí ó se so wípé àwon n sisé láti jé kí ìrìnàjò orí omi ...
Read More »Àwon akékòó ilé-èkó gíga Calabar is ayeye ìkékojáde won ní àrà òtò .
Àwon akékojáde ti ilé-ìwé giga Calabar (UNICAR) se ayeye ìkékojáde won ní àrà òtò. ” kò rorùn béè ni kò lera …ayò ni a ka gbogbo rè sí!!!”òkan nínú won ni ò pín èyí sí orí èro ayélujára (Facebook).
Read More »Olópàá kan ní orílè èdè Ghana fi pàsán na arábìnrin yí ní ìdí nítorí ó kò láti w’onú èwòn .
Olópàá tí ó n sojú àgó olópàá Domping ní orílè èdè Ghana, Ase Emmanuel Osei ni won ti fi èsùn kàn látàrí wípé ó fi pàsán na arábìnrin odún mókàndílógbòn (29) tí a mò sí Sarah Darko ní ...
Read More »Gbajúgbajà òsèré, Mercy Aigbe pín ìròyìn ìbànújé.
Òsèré, ìyá, àti oní káràkátà ti pín aí orí èro ayélujára láti polongo wípé bàbá òun ti dágbére f’áyé.
Read More »Jamil Balogun, omo Tiwa Savage yo pèlú àrà òtò nínú àwòrán tí ó yà.
Omokùnrin Tiwa Savage, Tunji ‘Tee Billz Balogun ti è ti rewà jù. Gbajúgbajà olórin Tiwa Savage pín àwòrán omo rè tí ó rewà, Jamil Balogun nàà yo ní àrà òtò nínú aso aláwò pupa tí ó yí orùn ká.
Read More »Buhari ti búra fún Boss Mustapha gégé bíi akòwé ìjoba gbogboogbò (SGF).
Àare Muhammadu Buhari ti se ìbúra fún akòwé ìjoba gbogboogbò tuntun tí ó n jé Boss Mustapha . Ayeye ìbúra náà wáyé ní yàrá ìgbìmò Ààre.
Read More »