A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé ...
Read More »
A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé ...
Read More »ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.
Read More »Arápájà di Igbákejì Alága ẹgbẹ́ PDP níhà Gúúsù Orílẹ̀ yìí Ọrẹ Akínṣọlá Ṣé bóṣe wu Ọlọ́run Ọba ní-ín sọlá, èèyàn tó bá wù Ú ní-Ìn ṣe lógo.Igbákejì gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ nígbààa kan, Ọ̀gbẹ́ni Taofeek Arapaja, ti jáwé olúbori sípò Ìgbákejì ...
Read More »Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣe aifẹsọ kebosi,lai rẹni jo o,ati pe n ta o ba fẹ o bajẹ,o ni bi o ṣe yẹ ka ṣe e,eyi lo bi atunse abẹnu lati fopin sawuye wuye to waye latari aawọ to suyọ laarin awọn ...
Read More »Ẹmu daada ní ń bẹ nínú aháÒgùrọ̀ àtàtà ní ń bẹ nílẹ̀ akèrèǹgbèỌtí ò dá, àlejò ò lọ!Ẹni ọtí kìí tí AdúmáadánAdúmáadán Àjèjémá gbádùn ara rẹ lọ! ‘Òògùn ibà ni, òògùn ibà ni,’Bí eré, bí eré ìyálé ilé mútí yó!Ẹmu ...
Read More »Gomina ipinle Ekiti, Dr Kayode Fayemi lo n salaye yii nibi eto ori telifison Kan ti arabinrin Morayo Afolabi n dari re.Leyin ti gomina dahun orisiirisii ibeere ni arabinrin naa wa tun beere asepo to wa laarin oun ati gomina ...
Read More »Edakun gbogbo ile, e fun mi ni owe to ni ile(house) ninu. E seun.
Read More »Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a si tun ku orire osu Ògún tuntun to bawa layo ati alaafia, osu naa yio sanwa sowo, somo, sile kiko, moto rira, ire oko/aya ati aiku baale oro yio ...
Read More »Ṣí Gbogbo Babaláwo àti Oníṣẹ̀ṣe lápapọ̀, Ní òní yìí (ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n, oṣù kejèe 2019) ni ìgbẹ́jọ́ tó bẹ̀rẹ̀ ní ìtàdògún tó kọjá lọ (Tuesday, 9th of July 2019) parí (tí ìdájọ́ sì wáyé pẹ̀lú) lórí ẹ̀sùn oyún síṣẹ́ fún ọ̀dọ́mọbìnrin tó ...
Read More »