Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, oni a sanwa sire gbogbo o ase. Odu ifa iwure toni ki bayi wipe: Òkan fìkìkìkì babalawo oladeji difa fun oladeji eyiti won nfojojumo njuwe re fun iku, won ni ...
Read More »Ijinle Ninu Oro Ifa Fi Ye Wa Nipa Bi Ila Se De Atelewo Wa.
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Ojó oni a san wa o ao ri tiwa se o ase. Gegebi awon opolopo eniyan se maa nsoro wipe “atewolabala ao meni to ko” lotito la ba ila latelewo wa sugbon imo ijinle ...
Read More »Ifa Iwure Toni Jade Ninu Odu Ifa Ogundigara
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku aseku odun o emin wa yio se pupo re laye awon alaseku yio bawa se o, ako ni rogun inira o ase. Ifa iwure toni jade ninu odu ifa Ogundigara Ifa naa ki ...
Read More »Odu Eji Ogbe
Ìpẹpẹrẹ ìmọ ni farabalẹ ni jogunda Adia fun Orunmila Ifa nlọ ba wọn mulẹ budo Nita Iku nita Arun, Nita Ajogun Mẹrẹrindilogun Te nbẹ lode oṣalaiye. Slender-Palm-Frond-is-Patient-In-Taking-Its-Revenge Revealed the way to Orunmila when he was looking for a place to ...
Read More »Ará Ọ̀run
Cc – Moyo Okediji
Read More »Ifa naa ki bayi wipe…
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin ku isimi opin ose, eledumare yio saanu wa o ao ri tiwa se loni, iyan jija koni ranwa lo sibiti ako fe o ase. Odu ifa ogbeweyin ni ...
Read More »Ifa Toni Ki Bayi Wipe
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, oni a san wa o, eledumare yio gbo ohun ebe adura wa o ase. Ifa toni ki bayi wipe: Orunmila ni ori a lana kan Moni ori a lana kan ...
Read More »Today’s Sermon – (Ijo Orunmila Ato) inc, Taken From Ejiogbe
My sermon today, Sat.3rd Sept. 2016 at our House of Worship, Indigene Faith of Africa( Ijo Orunmila Ato)Inc, taken from Ejiogbe:- Akole/ Theme Iwa onikaluku la o fi da l’ejo By their characters shall they be judged Isepe werewere ...
Read More »Odu Ifa Ose Meji/ Ose Olubadan
| | | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a si tun ku orire osu tuntun to tun soju emin wa o, eledumare yio muwa ...
Read More »Odu Ifa Ofun Meji/Orangun Meji Eepa Odu
| | | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a si ku imura toni, oro wa yio dayo loni o ase. Odu ifa ...
Read More »