Home / Tag Archives: Sanwo Olu

Tag Archives: Sanwo Olu

sanwoolu

Gómìnà Eko, Sanwó-Olú jẹ́jẹ̀ẹ́ ìrànwọ́ fún àwọn ọlọ́pàá tó lùgbàdi

Gómìnà Eko, Sanwó-Olú jẹ́jẹ̀ẹ́ ìrànwọ́ fún àwọn ọlọ́pàá tó lùgbàdi Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé wọ́n ní ìgbẹ̀yìn làásìgbò kan kìí bímọ tó rọ̀. Làásìgbò tó wáyé ní ìpínlẹ̀ Èkó láìpẹ́ yìí ti mú kí Gómìnà ìpińlẹ̀ náà, Babájídé Sanwó-Olú ó pàsẹ ...

Read More »
sanwoolu

Àánú àwo̩n tí kò gbàgbó̩ pé covid-19 wà ń se mí – Sanwo-olu

Àánú àwo̩n tí kò gbàgbó̩ pé covid-19 wà ń se mí – Sanwo-olu Gomina ipinle Eko,Alagba Babajide Sanwo-olu lo n salaye yii fun awon alase ati awon akekoo ile-iwe Corona ni ilu Eko.O ni o se oun laanu pe bi ...

Read More »

Sanwo-olu Máa Fún Ẹgbẹ̀rún Lọ́nà Igba Ènìyàn Lóúnjẹ L’eko

Nipa rogbodiyan ajakale arun coronavirus to n ja kaakiri agbaye to si tun ti rapala wo orileede Naijiria lati bii ose merin seyin. Ijoba ipinle Eko ti ti awon oja ti kii se ti ounje jijie ati mimu. Awon eniyan ...

Read More »

Sanwo-olu dáhùn ìbéèrè okada ló̩wó̩ aké̩kò̩ó̩ Chrisland

Sanwo-olu dáhùn ìbéèrè okada ló̩wó̩ aké̩kò̩ó̩ ChrislandLáti o̩wó̩ Yínká ÀlàbíGomina Babajide Sanwo-olu ti ipinle Eko lo n dahun orisiirisii ibeere lowo awon akekoo ile-iwe Chrisland to wa ni ilu Opebi ni Eko, nigba ti o gba won lalejo ni oni ...

Read More »