Awo Ori – Odu Odi Meji
Odidi kirimu kirimu, Awo Ori A difa fun Ori Ori n be logbere oun nikan Ebo won ni kowa se O gbebo nibe O rubo Kerekere Oju wa, Eti wa, Imu wa, Enu wa Gbogbo won wa ba Ori duro ...
Read More »
Odidi kirimu kirimu, Awo Ori A difa fun Ori Ori n be logbere oun nikan Ebo won ni kowa se O gbebo nibe O rubo Kerekere Oju wa, Eti wa, Imu wa, Enu wa Gbogbo won wa ba Ori duro ...
Read More »Hummmmmmmm igbiyanju lagbe ngba Olohun lomu isu ta #woo_orewa Nje o mo pe eni tio sun(sleep) lo nsun(move)????? ??? Gbiyanju lati tesiwaju loni majeki ijakule re fao seyin nigbesi aiye re #gbomi_dada Koseni tio ni #sugbon tie gboju re kuro ...
Read More »*Emi ko ni ku saaju ojo ayo mi.*Emi ko ni fi ewon logba.*Iji aye ko ni gbe mi lo(Ase Edumare). …………. #AKARA_IMORAN : Gbiyanju lati ni iwe iranti fun awon olooore re; ki o si gbiyanju lati fa iwe asise ...
Read More »Oro buruku pelerin erin’kkkkkk Mo sese ri eran ewure ni ibi to pokunso so ni in Eran ti moni ki a fe se odun lo pokunso yi ooo Mi o mon nkan to nba leru o erin’kkkkkk
Read More »Bi oro aye se ri ni yen oooo Bi poopo sin-sin odun se wa nta. Olodumare ti se bi o se nse fun awon ebi iya wa Bukky Ajayi Iya ti lo ni aro yi o. Gbogbo eyin Omo Ooduarere o ...
Read More »Oluwo Agbaye; Olori Awo Ode Isalaye; Ifa a mo oni mo ola bi Oba Olodumare; Igba eran ni a fi i bo’Fa; Aboruboye! Aboyeboru! Aboyebosise! cc- Yeyelufe IyaOgbe OmoEdu Oyewole
Read More »Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Idile Alayo wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Idile Alayo ti ose yi. ...
Read More »Iya nii je ta ni moo ri, Owo tabua nii je mo ba o tan Igba taa ba n wo sokoto penpe Baye ba ko ni lona Won le moju fira bi eni ofo se Boo rokele atata bu Aye ...
Read More »E MAA WI TELE MI : ………… *Osu yii, osu aseyori mi ni. *Osu iserere mi ni lase Edumare. *Osu igbega mi ni. *Osu idunnu mi ni. *Owo a fi ilee mi se ibugbe. *Akoba, adaba ko ni je temi. ...
Read More »