Idile Alayo: Oro owun si fe toju sumi
A ki gbogbo wa ku jimo oloyin toni a si ki wa ku abo sori eto Idile Alayo ti ose yi, gege bi ise wa atejise kan ti a ri gba lati owo okan lara won ololufe eto yi ni ...
Read More »
A ki gbogbo wa ku jimo oloyin toni a si ki wa ku abo sori eto Idile Alayo ti ose yi, gege bi ise wa atejise kan ti a ri gba lati owo okan lara won ololufe eto yi ni ...
Read More »Àsosùmósù ní í sawo àsosùmósù, Odún kì í dun ká má rìí ohun àjòdún. Olódùmarè á soore àrí tókasí fún ire láyé e eni iyì Oba Abel Simeon Olúwafémi bí e ti lé ódún kan lónìí. Àlékún owó, Àlékún ogbón, ...
Read More »OWE TONI Bi o ti wu ki oju orun funfun to, sanma dudu yo wa ,,…………………,…………………………………………. No matter how bright the sky clouds will exist(challenges aren’t unusuall)
Read More »:::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::: E MAA WI TELE MI : ……… *Edumare ma fi omo pa mi lekun. *Oluwa ma fi mi pa omo mi lekun. *Ogun aye koni bori mi. *Iji aye koni ja lu mi. *Inira ati idaamu, koni je temi. ...
Read More »Opele ide (brass divination chain)
Read More »TI O BA NI #500 KOSI KEROSINE KOSI GARRI TABI ELUBO OSI FE DA INA OKELE BAWO NI WA SE NA #500 fi se okele #antyfolashadealawada
Read More »E MAA WI TELE MI : …….. *Aye ko ni gbe ounje mi fun aja je. *Atije-atimu mi ko ni nira. *Oluwa so egan mi dogo. *Aye ko ni ta epo s’aso ala mi. *Fitila ogo mi ko ni ku. ...
Read More »Ojumo ti mo Eda ti ji saye Eda ti ko mose asela Ka ji ni kutu hai Ka gbegba pota Iya Akanke nko O ti re werenjeje Baba Talabi da O ti sare re kutuwenji Ki ni n le wa? ...
Read More »