Ẹ wọ ìbòmú tàbí kí ẹ rugi oyin – Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá
Ẹ wọ ìbòmú tàbí kí ẹ rugi oyin – Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Ọlọ́pàá èwo n tèpè ni àṣà tó gbayé kan tẹ́lẹ̀ , ṣùgbọ́n ní àsìkò kòró yìí, ó dà bí ẹni pé wọ́n ti sún ilé iṣẹ́ ọ̀hún kan ògiri ...
Read More »
Ẹ wọ ìbòmú tàbí kí ẹ rugi oyin – Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Ọlọ́pàá èwo n tèpè ni àṣà tó gbayé kan tẹ́lẹ̀ , ṣùgbọ́n ní àsìkò kòró yìí, ó dà bí ẹni pé wọ́n ti sún ilé iṣẹ́ ọ̀hún kan ògiri ...
Read More »Ó dà bí ẹni pé ń tí ń ṣe Lébáńdé kò s’ọmọ rẹ o, Lébáńdé ń sunkún ọmú, ìyá rẹ ń sunkún ebi, ló díá fún bí àjọ elétò ìdìbò Nàìjíríà ti kéde pé àjàkálẹ̀ àrùn apinni léèmí coronavirus kò ...
Read More »Aye̩ye̩ o̩jó̩ò̩bí Sikiru LemonBí a bá dájó̩, o̩jó̩, á pé, bí a dósù, osù á kò. Gbogbo o̩jó̩ ko̩kàndínló̩gbò̩n, osù ké̩rin o̩dún ni o̩jó̩ò̩bí Alhaji Sikiru Lemon. Yorùbá bò̩,wó̩n ní “àìbá wo̩n sí níbè̩ ni àìbá wo̩n dá síi”. Ìwé ...
Read More »Asiwaju agba fun egbe oselu APC, Asiwaju Bola Ahmmed Tinubu ni oun ko ni arun ajakale coronavirus bi gbogbo eniyan se n gbee poori enu. O ni awon kan ni oun ti wa ni igbele olojo merinla pelu Oluremi. Awon ...
Read More »Àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní bí iná ò bá tán láṣọ, ó seése kí ẹjẹ wọ̀rù wọ̀rù ṣẹ́kù lórí èékánná. À ti pé, ogun tí yóó bá wọ lé kóni, ọ̀nà la tií pàdé rẹ̀. Ìjọba ìpínlẹ̀ Kàdúná ti kéde ...
Read More »Iwure AJE Toni. Aje wa fii ile mii se ibugbe ❗❗❗ Aje iwo lobi Ogun ilu Aje iwo lobi Olufa Aje iwo lobi onipasan owere Oyale asin win bear asin win dolowo Oyale asi were oso asi were di aniyan-pataki Aje ...
Read More »Ògúndá Méjì.It is a fact that there is anxiety all over the World as a result of coronavirus pandemic. This is a challenge to all faiths. What else can we do other than supplication and offering. Looking at Odù, “Ògúndá ...
Read More »Ọọ̀nirìṣà ilé Ifẹ, jìngbìnì bí àtẹ àkún,Ọba Adéyẹyè Ẹnitan Ogunwusi bẹ̀rẹ̀ fínfín àwọn ìta gbangba gbogbo ní ìlú Ilé Ifẹ̀ lẹ́yìn tó kéde ríra àwọn ohun èlò afínko láti dẹ́kun ọwọ́jà àrùn apinni léèmí COVID-19. Ọba Adéyẹyè ra àwọn irinṣẹ́ ...
Read More »Ẹgbẹ́ àwọn nọ́ọ̀sì kan, National Nurses United ti fẹ̀hónúhàn ní gbàgede Ilé Ìjọba America, White House, láti késí àwọn Gómìnà àti Ìjọba àpapọ̀ pé kí wọ́n ó pèsè èròjà ìdáàbòbò ara ẹni fún àwọn òṣìṣẹ́ ètò ìlera tó ń gbógun ...
Read More »Ààrẹ Donald Trump ń tú bí ejò ní o , pé ọ̀pọ̀ ẹ̀mí ló ti sọnù látàrí pé China sahun òótọ́ ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ tí àlejò ọ̀ran náà tí fi ọ̀dọ̀ rẹ̀ ṣé bùba , kó tó wá di àǹkóò ...
Read More »