Igba otun de ba Majek Fashek: O korin ni Felabration
Bi Eledumare ba ran eda lowo, bi idan ni i ri. Majek Fashek ti opolopo sebi o ti tan fun latari bi okunrin naa se fi ogun oloro baye ara re je, ti ko si ni kobo lowo mo lati fi ...
Read More »
Bi Eledumare ba ran eda lowo, bi idan ni i ri. Majek Fashek ti opolopo sebi o ti tan fun latari bi okunrin naa se fi ogun oloro baye ara re je, ti ko si ni kobo lowo mo lati fi ...
Read More »BIG SHEFF ni yii, omo SALAWA ABENI. Sheriff Ilori je okan lara omo ti Queen Salawa Abeni bi fun Oba Fuji Alatika, Alhaji Rasaki Kolawole Ilori, eni ti gbogbo eniyan mo si Gen. Kollington Ayinla. Big Sheff je olorin Hip ...
Read More »Arabirin yii bi ibeta (omo meta) ni ipago ti won pese fun awon eniyan ti Boko Haram so di alainile lori to wa ni Bama ni ipinle Borno. @OlayemiOniroyin
Read More »Ijamba oko to waye lonii ni agbegbe. Ozumba Mbadiwe, VI, niluu Eko. Oko ajagbe akeru naa run mo awon oko bi merin kan nigba ti bireki re ko muu mo. Enikeni ko fara pa, dukia lasan lo sofo.
Read More »Obalufe ti Iremo-Ife, Oba Samuel Omisakin, eni to kangun si Ooni Ile-Ife, Oba Okunade Sijuwade gege bi igbakeji, to tun je olori awon afobaje ti ilu Ile-Ife naa ti dagbere faye lonii [15-10-15].
Read More »#Oniroyin Olayemioniroyin.com Taani obirin to wa ninu foto yii?
Read More »Arabirin yii bi ibeta (omo meta) ni ipago ti won pese fun awon eniyan ti Boko Haram so di alainile lori to wa ni Bama ni ipinle Borno. E wo linki isale yii: @OlayemiOniroyin
Read More »Ero o gbese ni olu ile ise awon olopaa ipinle Oyo to wa ni Eleyele nigba ti won se afihan awon igara olosa ajipata ati komu gbe fun awon oniroyin niluu Ibadan. Awon ole bi merin yii lagbo wi pe ...
Read More »Wahala ti bere si ni sele lori ayelukara bayii, eleyii si bere nikete ti Yemi Alade se afihan foto re pelu awon ore, eni to se apejuwe won gege awon ololufe orin re. Awon eniyan ko tile soro nipa Yemi ...
Read More »Eniyan le fi ebi kose owo, sugbon ko rorun lati febi kawe. Wahala igo ni o pa alasuota. Ise akanse, ka ji kawe loru, lo soke lo sode, ka sare wo kilaasi losan pon ganrin-ganrin ni o je komo ile ...
Read More »