Nje ohun to buru wa ninu ara bibo?
Nje ohun to buru wa ninu ara bibo? Idahun awon eniyan wa ninu linki isale yii: https://www.facebook.com/photo.php?fbid=904657846286766&set=gm.1070531176331524&type=3
Read More »
Nje ohun to buru wa ninu ara bibo? Idahun awon eniyan wa ninu linki isale yii: https://www.facebook.com/photo.php?fbid=904657846286766&set=gm.1070531176331524&type=3
Read More »Lose to koja ni iroyin nipa iku Taiwo Ibeji Oran fe si wa leti, e le ka iroyin naa ninu linki isale yii. www.olayemioniroyin.com/2015/10/ki-lo-sele-si-taiwo-leyin-iku-kehinde.html Iroyin naa ti fidi mule bayii. A si tun gbo wi pe won ti sin Taiwo ...
Read More »Awon omo orileede Iraq ti won sin orisii esin musulumi kan ti n je “Shia Islam” n fi obe ge awo ori ara won nibi won ti n gbadura.
Read More »Orisun Onka ede Yoruba 100-Ọgọrun 110- Adọfa, àádọ́fà 120- Ọgọfa 130- Aadoje 140- Ogoje 150- Adọjọ, àádọ́jọ 160-Ọgọjọ 170-Adọsan, àádọ́sán 180- Ọgọsan 190-Mẹwadinigba 200-Igba E tesiwaju ni isale lẹhin iwe Bireki yii (Continue after the page break bellow)
Read More »Funke Akindele ti pada si ni sere idaraya eleyii to n se lati din ara sisan re ku. Awon obirin onise tiata maa n se eleyii lati mu ara awon wa ni ipo odo, eleyii to se pataki si irufe ...
Read More »Aimoye ero wa pade Rotimi Ameachi nikete to jade ninu ile igbimo asofin Abuja lonii. Foto Rotimi Amaechi ati iyawo re leyin to yege niwaju ile igbimo asofin agba gege bi minisita ti won yan
Read More »Davido pada pade bobo to fi tattoo ya aworan omo baba olowo si igbaaya re. Ebun ti Davido fun naa ni alakorun ti won fi goolu se. O si so fun bobo naa wi pe awon ti di abi kan ...
Read More »#ToyinAimakhu Se igo yii o wa poju?
Read More »Okunrin arara yii ni won ti ri pelu awon alakatakiti esin Islam, Jabhat Al-Nusra niluu Syria. Jabhat Al-Nusra yii ni o ni ajosepo pelu iko AlQaeda eleyii ti Osama Bin Laden wa lara awon oludasile re ko to di wi ...
Read More »Leyin odun kan ti Kehinde Osuolale dagbere faye, iroyin mi-in tun ti kan wa wi pe ikeji re, Taiwo naa ti lo ba ikeji re lajule orun. Ohun ti a gbo ni wi pe ilu Abuja ni Taiwo ku si. ...
Read More »