Ijamba oko waye ni Victoria Island lonii
Ijamba oko to waye lonii ni agbegbe. Ozumba Mbadiwe, VI, niluu Eko. Oko ajagbe akeru naa run mo awon oko bi merin kan nigba ti bireki re ko muu mo. Enikeni ko fara pa, dukia lasan lo sofo.
Read More »
Ijamba oko to waye lonii ni agbegbe. Ozumba Mbadiwe, VI, niluu Eko. Oko ajagbe akeru naa run mo awon oko bi merin kan nigba ti bireki re ko muu mo. Enikeni ko fara pa, dukia lasan lo sofo.
Read More »Obalufe ti Iremo-Ife, Oba Samuel Omisakin, eni to kangun si Ooni Ile-Ife, Oba Okunade Sijuwade gege bi igbakeji, to tun je olori awon afobaje ti ilu Ile-Ife naa ti dagbere faye lonii [15-10-15].
Read More »#Oniroyin Olayemioniroyin.com Taani obirin to wa ninu foto yii?
Read More »Arabirin yii bi ibeta (omo meta) ni ipago ti won pese fun awon eniyan ti Boko Haram so di alainile lori to wa ni Bama ni ipinle Borno. E wo linki isale yii: @OlayemiOniroyin
Read More »Ero o gbese ni olu ile ise awon olopaa ipinle Oyo to wa ni Eleyele nigba ti won se afihan awon igara olosa ajipata ati komu gbe fun awon oniroyin niluu Ibadan. Awon ole bi merin yii lagbo wi pe ...
Read More »Wahala ti bere si ni sele lori ayelukara bayii, eleyii si bere nikete ti Yemi Alade se afihan foto re pelu awon ore, eni to se apejuwe won gege awon ololufe orin re. Awon eniyan ko tile soro nipa Yemi ...
Read More »Eniyan le fi ebi kose owo, sugbon ko rorun lati febi kawe. Wahala igo ni o pa alasuota. Ise akanse, ka ji kawe loru, lo soke lo sode, ka sare wo kilaasi losan pon ganrin-ganrin ni o je komo ile ...
Read More »E ku asiko yii eyin eniyan mi, ko to di wi pe n maa se alaye ara mi tabi abala Ogulutu to je tuntun to gori Iwe Iroyin Owuro. E je n sare bi yin nipa oun ti won pe ...
Read More »Kayeefi niluu Eko: omokunrin ti o lese n wa danfo. E le ka ero awon eniyan nipa okunrin yii nibi:
Read More »Ile itaja kan n ta masiini okada ati keke maruwa. Apapo gbogbo oja ti won ni je. meje (apapo okada ati keke maruwa), gbogbo oja won lapapo si ni taya mokandinlogun. Nje o le so iye okada ati keke maruwa ...
Read More »