Yeepa! Ki le yii?
O Dabi Eni Wi Pe Inu Osupa Ni Maanu Yii Ti Wa
Read More »
O Dabi Eni Wi Pe Inu Osupa Ni Maanu Yii Ti Wa
Read More »Lara awon iroyin wa to ti jade tele, awon iroyin lori ate Olayemi Oniroyin, mo se lalaye wi pe Edua Oke ko da ile Adulawo gege bi ibugbe awon otosi ati alaini; awon olori wa lo so ilu wa di ...
Read More »Ko to di wi pe ma kan lu agbami oselu ti n gbona felifeli bayii ni ilu Spain, nibi ti Arabirin Helen Mukoro to je omo ipinle Delta lati orileede Naijeria ti setan lati dije fun ipo aare orileede Spain, ...
Read More »Awon omo ile igbimo asofin Nigeria ti n foganna lojo to ti pe, ohun ti won se ni yii lodun 1962 nigba rogbodiyan Western Region. Orisun
Read More »YOMI FASH – LANSO Orisun +Wale Ojo-Lanre
Read More »Alase banki Fidelity ti Nigeria, Ogbeni Nnamdi Okonkwo ni Oniroyin Seun Oloketuyi gbe saye lori ikanni re, www.naijahottestgist.com wi pe oga banki naa feran ko maa se “yodiyodi” fun awon osisebirin banki re. O ni yato si awon osisebirin re, ...
Read More »Ikere Ektiti ni won ti pin. Atomode atagba, arugbo naa gba ninu iresi Fayose. Ohun ti awon eniyan so nipa re wa nibi:
Read More »Oko ajagbe eleru leyin kan jabo lati ori afara to wa ni Ojuelegba niluu Eko losan-an oni. Eniyan meji to wa ninu oko ti ajagbe naa jabo le lori fi ile aye sile loju-ese ti isele naa waye nigba ti ...
Read More »Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún. Ẹdúnjobí Ọmọ ẹdun tíí ṣeré orí igi Ọ́-bẹ́-kẹ́ṣé-bẹ́-kàṣà, Ó fẹsẹ̀ méjèèjì bẹ sílé alákìísa; Ó salákìísà donígba aṣọ. Gbajúmọ̀ ọmọ tíí gbàkúnlẹ̀ ìyá, Tíí gbàdọ̀bálẹ̀ lọ́wọ́ baba tó bí í lọ́mọ. Wínrinwínrin lójú orogún Ejìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ...
Read More »Omobirin odaran kan ni owo awon olopaa ti te ni agbegbe Ketu niluu Eko pelu bo se fi ero ayoonu iloso jo omo egbon re ti n gbe pelu re, Bimpe Badmus, omo odun merindinlogun, nidi pelu esun wi pe ...
Read More »