Se N’Ibadan Tia Nile Oluyole?
Ibadan tia! Se n’Ibadan tia? Ibo lawa o mo lOluyole Ibadan? MAPO d’AYẸYẸ Gbogbo ODÍNJÓ tia ni, ELEKURỌ, ALEKUSỌ, Ibo gan-an lawa o mo n’Ibadan? BẸRẸ titi to fi de ÒÓPÓ Yoosa, Ibi to ku taa mo ni ke e ...
Read More »
Ibadan tia! Se n’Ibadan tia? Ibo lawa o mo lOluyole Ibadan? MAPO d’AYẸYẸ Gbogbo ODÍNJÓ tia ni, ELEKURỌ, ALEKUSỌ, Ibo gan-an lawa o mo n’Ibadan? BẸRẸ titi to fi de ÒÓPÓ Yoosa, Ibi to ku taa mo ni ke e ...
Read More »Tai Solarin dilu nla Tai Solarin ile ẹkọ nla to dilu nla. Ibi ọgbọn gbe pamọ si. Arọni imọ ti n ja ni laya bi oke. Gbékanlùkan isẹ ọpọlọ to fakíki. Kinihun o jẹran ikaṣi. To ba jọ bi irọ, ...
Read More »Okan lara awon aworan to jade lati ipinle Bauchi sori ayelukara lojo odun ileya to koja ni yii. Lotito, olopaa ko le mu won. Nitori olopaa kan wo won lotito ko si le da won duro. Sebi odun lo de.
Read More »Eyin eniyan mi, ohun kan se pataki ti mo fe ko da wa loju; ti mo si fe ki oye re ye wa gidi. Igbe aye eniyan wa ninu oro siso tabi ohun ti a fenu se ijewo re. Iru ...
Read More »Oni, 27-09-2015, ni Bisoobu Dafiidi Olaniyi Oyedepo pe eni odun mokanlelogota (61). Omo bibi Omu Aran ni ipinle Kwara ni i se, oun kan naa ni oluso aguntan agba fun ijo Living Faith Ministry to kari aye pata. Onkowe ni, olukoni oro ...
Read More »Okuta ati ogulutu ni awon eniyan bere si ni so lu aare ile igbimo asofin agba, Bukola Saraki, laaaro oni nibi to ti fe kirun yidi odun ileya niluu Ilorin Afonja. Bi awon eniyan se n ju okuta bee naa ...
Read More »Ni ile Yorubawa, ti omo kekere ba n paro, awon agba gba wi pe iru omo naa le jale tabi ko ti maa jale. Lara esun metala ti eka onidajo ti Code of Conduct Bureau, Code of Conduct Tribunal gbe ...
Read More »E leyii tun leku!
Read More »Ki e to tesiwaju lati ka abala keji iroyin yii, maa royin ki e ka abala kinni na. Eleyii yoo fun yin ni oye ibi ti alaye naa ti bere. E le ka iroyin naa ninu linki isale yii: Bi ...
Read More »Nje awon eniyan omo Nigeria si ni igbagbo wi pe Naijeria sile goke agba? E se ayewo linki isale yii lati ka ero awon omo Nigeria:
Read More »