Ebola seruba awon eniyan niluu Calabar
O kere tan, awon eniyan bi mewaa ni won ti se ayewo fun bayii niluu Calabar latari wi pe won ni ibapade pelu okunrin kan ti won fura si wi pe oseese ko ni arun Ebola. Okunrun ti won fura ...
Read More »
O kere tan, awon eniyan bi mewaa ni won ti se ayewo fun bayii niluu Calabar latari wi pe won ni ibapade pelu okunrin kan ti won fura si wi pe oseese ko ni arun Ebola. Okunrun ti won fura ...
Read More »Leyin bi odun mewaa ti Rose Odika ti wa gege bi iya-n-dagbe, oserebirin omo Ipinle Delta naa ti setan lati ni oko tuntun. Bi o tile je wi pe bonkele ni won fi oro naa se, ti won si n ...
Read More »Orisun Mercy Aigbe-Gentry, okan ninu awon oserebirin onirawo meje ile Naijiria, dana ayeye ojo ibi to peleke fun oko re, Lanre Gentry, eni to pe omo aadota (50) odun lose to koja. “Eni ma segbeyawo a se gudugudu meje” l’Oritse ...
Read More »Okunrin olopaa kan ti eka ti Ipinle Ondo, Ogbeni Israel Omowa ni iyawo re, Arabirin Wumi Omowa ti gun lobe pa nibi gogongo orun oko re. Ede aiyede kan lo waye laaarin toko-taya ti won gbe ni agbegbe Olu to ...
Read More »Gomina Akinwunmi Ambode ti Ipinle Eko gbe ami-eye fun gomina Ipinle Eko ana, Barisita Babatunde Fasola nibi ayeye weje-wemu olodoodun awon amofin ti Ipinle Eko Gomina Akinwunmi Ambode eni to je alejo pataki nibi ayeye ti won pe ni Legal ...
Read More »*O ko sowo olopaa nibi o ti fe fi owo eru ra ile ni London. *Ile ejo gbe ese le owo re mole *Iya re naa ti foju ba ile ejo. *Agbejoro re kede wi pe o ni arun jejere ...
Read More »Iwo taa lo gbeja ninu awon meteeta?
Read More »Ile ejo ti fagile eto idibo to gbe Senator Buruji Kashamu wole sile igbimo asofin agba Abuja lati soju Ogun. Won ni magomago po ninu eto idibo naa, ati wi pe won yoo tun ibo naa di ni.
Read More »Ebora ilu Owu di Ebora agbaye: Won Fi Obasanjo je siamaanu awon aare orileede agbaye to ti feyin ti Aare ile Naijiria nigba kan ri, Olusegun Aremu Obasanjo baba Iyabo ni won ti yan bayii gege bi siamaanu igbimo egbe ...
Read More »Ti eyin ko ba tii ra iwe Iroyin Owuro to jade lose yii, a je wi pe iroyin ku sibi kan te e ti gbo. Lati ori oro oselu de amuludun, awon oro to n lo ati igbelaruge asa ati ...
Read More »