Odún pé, odún jo, àmòdún wa èsín pé.
Ikú bàbá yèyé, Aláse èkejì Òrìsà, baba wa Aláàfin ti ilè Òyò, Oba Lamidi Adeyemi 111 se ayeye ojó ìbí rè ní òní tí won pé ogórin odún (80). Àrà méèrírí ni kábíèsí, Ikú bàbá yèyé nítorí baba ni wón ...
Read More »
Ikú bàbá yèyé, Aláse èkejì Òrìsà, baba wa Aláàfin ti ilè Òyò, Oba Lamidi Adeyemi 111 se ayeye ojó ìbí rè ní òní tí won pé ogórin odún (80). Àrà méèrírí ni kábíèsí, Ikú bàbá yèyé nítorí baba ni wón ...
Read More »Ìròyìn jé kí á mò wípé arábìnrin yí ya wèrè léyìn tí eni tí ó ti láya nílé ba lájosepò tán. Gégé bí eni tí ó sún mo se so. Ó so wípé ó ti mo omobìnrin yí lára kí ...
Read More »Arábìnrin kan ni aso rè fàya ní enu ìdí látàrí àsejú rè nípa ijó tí ó fé kó mólè dáadáa, kí ó tún owó ijó náà mú láti ilè. Nínú fídíò tí a rí wò, tí a ti yo àwòrán ...
Read More »Òkan lára ilé ìgbé àwon Akékòó ti ilé-èkó gíga ifafitì ti Obafemi Awolowo gbiná ní alé àná. Ilé ìgbé yìí a máa jé Alumni hostel, bí ó ti lè je wípé a kò fi tara tara mo bí ó se ...
Read More »Tí won bá ni èèyàn apanilérìn ni baba won kò paró rárá, nítorí àwon gangan ni oyè adérìn-ín-p’òsónú ye. Moses Olaiya Adejuwon (M.O.N), lórúko baba súgbón bàbá Sala ti gba orúko lówó won. Àsé kò sí eni tí kò ní ...
Read More »Ìyá omo keta gbajúgbajà olórin tí a mò sí Wizkid, tí orúko ìyà omo náà a máa jé Jada Pollock pín àwòrán omo rè, Zion. Alámójútó Olórin àgbáyé, Wizkid tí ó padà di ìyá omo rè, Jada Pollock pín àwòrán ...
Read More »Gbajúgbajà elétíofe tí gbogbo ayé mò sí Linda Ikeji tí ó sèsè bí omo okúnrin rè ní ojó ketàdínlógún osú kesàn-án odún tí a wà yí, pín àwòrán sí orí èro insítágírámù pèlú omo rè, Jayce. Ó ko síbè wípé… ...
Read More »Àtẹ́lẹwọ́ mi ọ̀tún ni mo fi kọ́’fá ń dídá Mo mọ Ifá ń dídá A dífá fún Akítán tíí ṣe ọmọ’yè Oníkàá Àtẹ́lẹwọ́ mi òsì ni mo fi kọ́bò ní gbígbà Mo mọ ìbò ni gbígbà Dífá fá fún Aṣọ̀gbà ...
Read More »Ejìnrìn wọ̀jọ ̀wọ̀jọ̀ Awo Ọlọ́wọ̀ ló ṣefá fún Ọlọ́wọ̀ Eléyìí tí yóò roko roko tí yóò gbé kílìṣí tíí ṣe yèyé ajé wálé Ìji lẹ́lẹ́ – Awo Ìji lẹ́lẹ́ Ìji lẹ̀lẹ̀ – Awo Ìji lẹ̀lẹ̀ Ẹ̀fúùfù lẹ̀lẹ̀ ní jági lọ́run ...
Read More »