Home / Test2page 4

Test2

mko

Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ àwọn tó f’ọ́lé e MKO Abiola

Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ àwọn tó f’ọ́lé e MKO Abiola À ṣẹ kò sééyan táyé ò lé bá ṣọ̀tá, ó tún hàn pé wọ́n le bínú òkú ọ̀run , yàtọ̀ sèèyan tí wọ́n jọ ń wà láyé. À bí kín ní ...

Read More »

Ìjọba Nàìjíríà kéde ìlànà tuntun fún ìséde Kofi-19

Ìjọba Nàìjíríà kéde ìlànà tuntun fún ìséde Kofi-19 Ṣe àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní kò sí ohun kan tó le le le tí kìí padà rọ̀, ìdí nìyí tó fí jẹ́ pé, ìrọ́jú ló yẹ ẹni tí eégún bá ń ...

Read More »

Ìrọ̀rùn dé, Yínká Ayéfẹ́lẹ́ le è dúró kọrin báyìí

Ìrọ̀rùn dé, Yínká Ayéfẹ́lẹ́ le è dúró kọrin báyìí Ẹ̀dá tí tó bá sì wà lókè èèpẹ̀ tó ń ṣẹ̀mí, ìrètí kò pin fúnrúfẹ́ onítọ̀ùn, bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ lọ̀rọ̀ rí fún gbajúgbajà olórin jùjú n-nì, Yínká Ayéfẹ́lẹ́ bí ó ti jẹ́ ...

Read More »

Wọ́n ti yan adarí tuntun fún Ifásitì “Unilag”

Ó jọ bíi ẹni pé kángun kàngùn kángun ilé ẹ̀kọ́ Ifásitì ìpínlẹ̀ Èkó tí kángun síbi kan báyìí o, bí Ìròyìn tó ń tẹ̀ wá lọ́wọ́ ṣe ń fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé àwọn aláṣẹ Ilé ẹ̀kọ́ gíga Ifásitì Èkó, Unilag ...

Read More »

Sunday Shodipe tí wà láhàámọ wa– Alukoro ọlọ́pàá Ọ̀yọ́

Sunday Shodipe tí wà láhàámọ wa– Alukoro ọlọ́pàá Ọ̀yọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Ilé iṣẹ́ Ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti sọ ọ̀rọ̀ kanranjágbọ́n afurasí Sunday Shodipe di ẹgbẹ̀rún ìsáǹsá tí wọn ò lè sá mọ́ Ọlọ́run lọ́wọ́, bí ìròyìn tó ń tẹ̀wà lọ́wọ́ ...

Read More »

A ti mú afurasí tó ń jẹ igbẹ níbàdàn–Ilé iṣẹ́ Ọlọ́pàá

A ti mú afurasí tó ń jẹ igbẹ níbàdàn–Ilé iṣẹ́ Ọlọ́pàá Ayé ń lọ sópin, ohun tétí ò fẹ́ ẹ̀ gbọ́ rí lojú ń rí báyìí o.Ilé iṣẹ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní ìwádìí ti bẹ̀rẹ̀ ní pẹrẹwu lóri ọkùnrin kan ...

Read More »

Bishop Oyedepo ní láti tẹ̀lé òfin tàbí kí ó dá orílèèdè tirẹ̀ sílẹ̀ – Iléesẹ́ Ààrẹ

Oludasile ile ijosinLiving Faith Church Worldwide, Bishop David Oyedepo lo ti n gbe peregi kana pelu ijoba apapo lati bii odun meloo kan seyin. Ofin lori owo ori ati amojuto awon ile-ise ati awon ile-ijosin ti ajo Company and Allied ...

Read More »

Iyawo Oloju Buluu

‘Kìí ṣe tìtorí owó ni mo ṣe fẹ́ gba Risikat padá, mo ní ìfẹ́ ẹ rẹ̀ ni ‘ Wasiu Jimoh, ọkọ Risikat tó ní ojú búlúù ní Ilọrin bá BBC Yorùbá sọ̀rọ̀, ìyàwó rẹ̀ náà fèsì. Iyawo Oloju Buluu Ẹ ...

Read More »

Họ́wù! Àgọ́ ọlọ́pàá ni wọ́n tí fọmọ odó lu èèyàn méjì pa

Họ́wù! Àgọ́ ọlọ́pàá n wọ́n tí fọmọ odó lu èèyàn méjì pa Ará kò níí tán nílé alárà láé láé. À bí kínni kí á tí wí pẹ̀lú bí èèyàn méjì ti kú lẹ́yìn tí ọlọ́pàá kan fi ọmọ odó ...

Read More »

Ẹlẹ́buùbọn gba ìpàdé àwọn ẹlẹyẹ ẹ̀ka ti Ọ̀ṣun

Ẹlẹ́buùbọn gba ìpàdé àwọn ẹlẹyẹ ẹ̀ka ti Ọ̀ṣun Fẹ́mi Akínṣọlá Gbajúgbajà onímọ̀ nípa ìṣègùn ìbílẹ̀ nílẹ̀ ẹ Yorùbá, tó tún jẹ́ Olóyè Àràbà nípìńlẹ̀ Oṣun. Ifáyemí Ẹlẹ́buùbọn ti gba ìpàdé ńlá àjọ̀dún ayẹyẹ àpapọ̀ ẹgbẹ́ àwọn oṣó àti àjẹ́ ní ...

Read More »