Home / Test2page 5

Test2

janduku

Jàǹdùkú pa ọlọ́pàá méjì, jó àgọ́ wọn mẹ́wàá, báńkì mẹ́ta, jí ọ̀pọ̀ owó l’Ékó -iléeṣẹ́ ọlọ́pàá

Jàǹdùkú pa ọlọ́pàá méjì, jó àgọ́ wọn mẹ́wàá, báńkì mẹ́ta, jí ọ̀pọ̀ owó l’Ékó -iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Fẹ́mi Akínṣọlá Àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní, ìjàngbọ̀n kìí dúró síbi tó bá rọ̀, bí kò ṣe ibi tó bá le koko. Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ...

Read More »
sanwo

Ìṣẹ̀lẹ̀ Lekki, Ẹ̀ẹ̀mejì ni mo pe Ààrẹ Buhari lánàá , àmọ́ ń kò ri bá sọ̀rọ̀ – Sanwo-Olu

Ìṣẹ̀lẹ̀ Lekki, Ẹ̀ẹ̀mejì ni mo pe Ààrẹ Buhari lánàá , àmọ́ ń kò ri bá sọ̀rọ̀ – Sanwo-Olu Fẹ́mi Akínṣọlá Bí ọ̀rọ̀ ńlá kò bá tíì tán èèyàn ńlá kò ní tíì sinmi àròyé Sanwo-Olu tíí se Gómìnà wọn ní ...

Read More »
ooni obj

#EndSARS: Obasanjọ, Ọọ̀ni sọ̀rọ̀ lórí ìwọ́de tó ń lọ lọ́wọ́

EndSARS:Obasanjọ, Ọọ̀ni sọ̀rọ̀ lórí ìwọ́de tó ń lọ lọ́wọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Àgbà tí òye yé kan kìí wà lọja, kí orí ọmọ tuntun wọ́, ìdí rèé tí àwọn àgbà kàn-aǹ-rìn méjì nílẹ̀ Yorùbá fi forí korí lórí ìwọ́de EndSARS tó ...

Read More »

Buhari kí Obaseki kú oríire

Buhari kí Obaseki kú oríire Ààrẹ Muhammadu Buhari ti ránṣẹ́ kú orííre sí Godwin Obaseki lẹ́yìn tó jáwé olúborí nínú ìdìbò gómìnà tó wáye lónìí nípìnlẹ̀ Edo. Obaseki tó jẹ́ olùdíje dupò gómìnà lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú PDP ló fi ìdí ...

Read More »
ooni

Ọ̀ọ̀ni lfẹ̀ wọ ilédì fún ọdún ọlọ́jọ́

Ọ̀ọ̀ni lfẹ̀ wọ ilédì fún ọdún ọlọ́jọ́ Bí a bá ń ṣọ̀rọ̀ ọ̀nà, yóó sòro púpọ̀ kí á tó yọ tí ẹsẹ̀ kúrò.Bí a bá sì ń ṣọ̀rọ̀ nípa ìṣẹ̀ṣe, òpó kan jàǹràn ni ilé Ifẹ̀ níbi tí ó ti ...

Read More »

Odù, Ìwòrì bogbè cast for today’s Òsè Ifá

Looking at the Odù, Ìwòrì bogbè cast for today’s Òsè Ifá, it could be said that sometimes our detractors feel they are hurting us but they don’t know they are pushing us to wealth. Just listen to this stanza from ...

Read More »

Tinubu, má dàá sí ọ̀rọ̀ ìdìbò gómìnà Edo–PDP kìlọ̀

Tinubu, má dàá sí ọ̀rọ̀ ìdìbò gómìnà Edo–PDP kìlọ̀ Ṣé látàrí a á sìnlú a à sìnlú yìí náà lọ̀rọ̀ wá di fàá ká já a báyìí, tí àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú ń jùkò ọ̀rọ̀ lu ra wọn.Nífèsì padà sí n ...

Read More »

Òṣìṣẹ́ mẹ́rin bọ́ sí gbaga ọlọ́pàá lórí ikú ọ̀gá wọn tó rì sómi

Ìgbákejì Ọ̀gá Àgbà iléeṣẹ́ tó ń rí sí ọ̀rọ̀ owó orí, Price Water Coopers , PwC Nigeria , Tola Ogundipẹ ti jáde láyé. Ọjọ́ Sátidé ni wọ́n ti bẹ̀rẹ̀ sí ní wá arákùnrin náà lẹ́yìn tó wọ ọkọ̀ ojú omi ...

Read More »
mko

Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ àwọn tó f’ọ́lé e MKO Abiola

Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ àwọn tó f’ọ́lé e MKO Abiola À ṣẹ kò sééyan táyé ò lé bá ṣọ̀tá, ó tún hàn pé wọ́n le bínú òkú ọ̀run , yàtọ̀ sèèyan tí wọ́n jọ ń wà láyé. À bí kín ní ...

Read More »

Ìjọba Nàìjíríà kéde ìlànà tuntun fún ìséde Kofi-19

Ìjọba Nàìjíríà kéde ìlànà tuntun fún ìséde Kofi-19 Ṣe àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní kò sí ohun kan tó le le le tí kìí padà rọ̀, ìdí nìyí tó fí jẹ́ pé, ìrọ́jú ló yẹ ẹni tí eégún bá ń ...

Read More »