Arábìnrin tí ó n gba ààwè funfun fún Wizkid láti ségun àwon òtá rè.
Odóbìnrin kan ní orílè èdè Nàíjíríà, Bosslady ni orúko rè n jé ní orí èro ayélujára (Instagram) ti jé kí ó di mímò wípé òun n gba ààwè funfun fún Wizkid, nítorí bí ó se so ó ní Wizkid ní ...
Read More »
Àṣà Oòduà Àṣà Oòduà
