Omoba Eze Madumere àti Chioma Rosemary kí omobìnrin kú àbò.
Igbékejì Gómìnà ìpínlè Imo , Omoba Eze Madumere àti aya tí ó sèsè fé, Omoba Chioma Rosemary Madumere kí omobìnrin káàbò léyìn osù méjì léyìn ìgbéyàwó, won ti bí omobìnrin. Igbékejì Gómìnà ni ó pín àwòrán yí tí ...
Read More »