Ay lo kí Gómìnà Okorocha , ère ti e náà n bò lónà, àwon olólùfé rè ni ó so béè.
Báyìí ni adérìnpòsónú AY tí ó sèsè dé láti Dubai fún ìsinmi pín àwòrán òun àti Gómìnà ìpínlè Imo, Rochas Okorocha nígbà tí ó lo ki n’ílé, tí àwon olólùfé rè sì so wípé ère ti è náà kò ...
Read More »