Ódára kí èèyàn San ìdàméwàá, D’banj ni ó so béè .
D’banj pín èróngbà rè nípa ìdàméwàá. E jè rí, àwon omo Nàíjíríà ti da l’óhùn bí ó ti yé.
Read More »
D’banj pín èróngbà rè nípa ìdàméwàá. E jè rí, àwon omo Nàíjíríà ti da l’óhùn bí ó ti yé.
Read More »Cristiano Ronaldo ti kí omo rè kerin káàbò, Alana Martina ni orúko rè. E kú oríre Ooo.
Read More »Gégé bí ò n lò èro ayélujára (Facebook)se so, odókùnrin yí ye kí ó se ìgbéyàwó ni osù kejìlá sùgbón ó ti di olóògbé. Ó kú nínú ìjàmbá pèlú àwon tí ó kùn rè. Kí olórun te sí aféfé rere. ...
Read More »Wizkid pa Davido, Techno àti àwon míràn tí ó wá fún àmì èye AFRIMA ti odún yí láyò. Wizkid gba èbùn fún orin rè ” Come closer ” tí ó ko pèlú Drake.
Read More »Òsèré orílè èdè Ghana, Jackie Appiah, èyí rewà ju kí èèyàn fi ojú paáré lo, òsèré yí ló pin sí orí èro ayélujára láti pín àwòrán tí ó rewà yí níbi tíó ti wo aso ìbílè tí a mò ...
Read More »Òsèré Ebube Nwagbo tí ó wà ní ìsinmi lówólówó ní Dubai ti pin sí orí èro ayélujára (Instagram) àwòrán aso ìwè rè pèlú bí ó se n wè l’ódò àti eja nlá tí ó n jé Dolphin .
Read More »Òsèré orílè èdè Ghana , Nana Akua Addo ya ni lénu pèlú ìmúra rè lo sí AFRIMA odún yí.
Read More »Òdóbìnrin olórin àkókó ní ikò Marvins , Tiwa Savage gbé igbá orókè ní ibi àmì èye AFRIMA ti odún yí gégé obìnrin àkókó ní ikò adúláwò ti odún yí. Tiwa Savage pa Yemi Alade, Aramide àti Seyi Shey ...
Read More »Léyìn isé abe ; Hushpuppi káàbámò, ó sì gba àwon èèyàn n’ímòràn.
Read More »Sèbé nlá ni won pa ní agbègbè Ofoni ní ìjoba ìbílè Sagbama ní ìpínlè Bayelsa . E wo bí won se ge fún obè aláta yéríyérí.
Read More »