Aisha El-Rufai se àgbékalè ètò abéré àjesára àti láti lé ìta lo l’ára omodé.
Gégé bí Gómìnà ìpínlé Kaduna se pin, El Rufai. “Aisha El-Rufai ti se àgbékalè abéré àjesára àti ìpolongo láti lé ìta lo l’ára omodé.
Read More »
Gégé bí Gómìnà ìpínlé Kaduna se pin, El Rufai. “Aisha El-Rufai ti se àgbékalè abéré àjesára àti ìpolongo láti lé ìta lo l’ára omodé.
Read More »Stephanie Coker tún yo ní àrà òtò, ó tún yanilénu nínú àwòrán tuntun tí ó sèsè yà. Stephanie Coker ti se ìgbéyàwó láìpé ojó, tí a bá ní p’aró ìgbéyàwó náà ye é…
Read More »Omobìnrin kejì ti gbajúgbajà olórin ní orílè èdè Nàijíríà , Davido , omo tí kò tíì fi esè kan ilè baba rè rí, ni ó ti n dàgbà sínú ewà , ó ti è ti rewà jù nínú àwòrán ...
Read More »Bí ó bá jé ti erú tí won kó wa ni kì bá da, bí kò se ikú burúkú tí won fi n pa àwon baba nlá wa. Béè won kò dá owó dúró. Kí Elédùmarè gbà wá lówó ...
Read More »Yannick Arnauld Engolo láti orílè èdè Cameroon tí ó sì jé ènìyàn Swiss tí ó dá Miscas àti priceless corporation sílè ni a ti fi èsùn kàn látàrí wípé ó pa àwon omo rè méta. Ó ti è pe ...
Read More »Àwon omo egbé òkùnkùn Eiye àti Àíyè ti so wípé àwon kò se mó nígbà tí won se ìwóde gbangba ní ìpínlè Èkó.
Read More »Olga, ìyàwó ògbóntàrigì agbá bóòlù Mikel Obi, pín àwòrán ara rè nígbà tí ó n bá àwon omo rè seré , tí ó sì n ka ìwé fún won .
Read More »Ààre ilé-ìgbìmò asòfin Bukola Saraki pàdé Akòwé ìjoba gbogbogbò tuntun (SGF)Boss Mustapha.
Read More »Dr. Akinwumi Ambode, Gómìnà ìpínlè Èkó se ayeye láti we okò ojú omi tí ó sèsè rà, okò ojú omi náà sì wà fún ìpínlè Èkó, bí ó se so wípé àwon n sisé láti jé kí ìrìnàjò orí omi ...
Read More »Àwon akékojáde ti ilé-ìwé giga Calabar (UNICAR) se ayeye ìkékojáde won ní àrà òtò. ” kò rorùn béè ni kò lera …ayò ni a ka gbogbo rè sí!!!”òkan nínú won ni ò pín èyí sí orí èro ayélujára (Facebook).
Read More »