Awakò okò epo NNPC pa arákùnrin kan ní Aba.
Gégé bí Sopu tí ó n gbé ní Aba se so, olóògbé tí àwòrán rè hàn n’ísàlé yí ní awakò okò epo ti NNPC pa. Òpòlopò ènìyàn sì péjo láti ya àwòrán rè láti jé kí àwon mòlébí ...
Read More »
Gégé bí Sopu tí ó n gbé ní Aba se so, olóògbé tí àwòrán rè hàn n’ísàlé yí ní awakò okò epo ti NNPC pa. Òpòlopò ènìyàn sì péjo láti ya àwòrán rè láti jé kí àwon mòlébí ...
Read More »Àwon òsèré tí ewà won ya ni lénu tí ó sì pa ni kú ni àwon ìbejì yí . Treasure àti Tracy Daniel tún lé odún kan si . Àwon ìbejì yí ti hàn ní àìmoye eré orí ...
Read More »Ó ti pé tí a ti rí àwòrán Wande coal. Sùgbón èyí fi hàn wípé òré sì ni àwon méjèèjì…
Read More »Gégé bí ìtàn se so è yun-ùn tí won pín sí orí èro ayélujára (IG) ti Joro Olumofin. Òdómobìnrin tí ó gba òrékùnrin rè tí kò n’ísé l’ówó gbé nínú ilé rè ní Eko padà délé láti ìrìn-àjò ...
Read More »Afárá (Bridge ) yí ni òjò ti gbá dànù láti bí osù díè séyìn látàrí òjò nlá tí ó rò tí àwon ìjoba kò sì se nkankan si . ònà alágbàdo ni afárá yí wà . Nígbà ...
Read More »Òré Davido, tí ó n jé Tagbo Ifeatuchukwu Umueike ni ó sùn re ní ogún’jó osù kèwá odún, 2017 (20/10/2017) ní ìlú tí a bi sí. Ní ìjoba ìbílè Osumenyi ní ìpínlè Anambra . Àwon òré ...
Read More »Òdómobìnrin odún mókàndínlógún tí ó tún jé ò n lò èro ayárabíàsá (Twitter) ti gba àwon òdóbìnrin ní ìmòràn wípé kí won múra sísé kí won sì gbàgbó nípa èróngbà olórun sí won nígbà tí ó n ...
Read More »Òdómokùrin kan ni orílè-èdè Ghana ni ó pa ara rè léyìn ojó díè tí ó pín nípa àwon ebí rè tí kò gbà fun kí ó fé ìyá omo rè….
Read More »E wo àwòrán tipétipé Gómìnà Rochas Okorocha àti ìyàwó rè tí ó rewà, Nneoma Nkechi Rochas Okorocha. Àgbà wá búra bí èwe ò bá se ó rí…
Read More »Àfòròdárà (Rapper) Gucci Mane àti Keyshia Ka’oir se ìgbéyàwó alárinrin tí ó jé wípé ogún-l’ógbòn àwon ènìyàn ni won wò ó n’ílé l’óko lórí èro amóhùnmáwòrán.igbéyàwó náà rinlè gan tí ó fi jé wípé àwon ènìyàn jàkànjàkàn ...
Read More »