Ejò tí mo pa nínú ilé Adìe mi lóòní.
Ní òní mo gbèrò láti tún ilé àti àyíká Adìe mi se, ni mo pàdé afayàfà yí, mo sá eré bí mo se le sa mo. Nítorí ìgbà àkókò mi rè é tí mà rí ejò ńlá báyìí láàyè, tí ...
Read More »
Ní òní mo gbèrò láti tún ilé àti àyíká Adìe mi se, ni mo pàdé afayàfà yí, mo sá eré bí mo se le sa mo. Nítorí ìgbà àkókò mi rè é tí mà rí ejò ńlá báyìí láàyè, tí ...
Read More »Timi Àgbàlé, olóde tí ó sì jé jagunjagun tí Aláàfin rán lo sí ìlú Ede láti dáàbò bo àwon ènìyàn ibè. Alágbára ènìyàn ni Timi jé , tí a sì mò ó sí *Timi Àgbàlé olófà-iná*,gégé bí ìtàn se so, ...
Read More »Ìlú kéréje kan wà ní ìpínlè Oyo tí orúko ìlú náà sì ń jé *ADO AWAYE*, òdó kàyééfi kan wà ní ìlú yí tí ó jé wípé bí ènìyàn bá ti esè kan bo inú rè yóò fa eni náà ...
Read More »Àwòrán tí ó gba aféfé ni ti àwon tokotayà yí tí oko jé odún mókàndílógún tí ìyàwó sì jé odún méèdógún ní ilè àríwá orílè èdè Nàìjíríà. Ò n lò èro ayélujàra kan ni ó pín àwòrán tokotayà yí, tí ...
Read More »Ogbà Obafemi Awolowo University (OAU) ti kó sí inú dàrúdàpò nígbà tí òpò akékòó tò lo sí àgó olóòpá tí ó wà ní Moore ní ìlú ile-ife láti bèèrè fún ìdásílè àwon akegbé won tí àwon ìgbìmò ìdábòbò Ogbà náà ...
Read More »Ní’sàlé ni àwòrán ìsìnkú olóyè nínú ológun (Corporal) Odudu Davis tí ìbon pa nígbà tí osù kàrún di ogbòn ní inú odún yìí (30/5/2017)láti owó àwon olóòpá ojú omi (naval officer) nígbà tí àwon olóòpá àti àwon olóòpá ojú ...
Read More »A kú àyájó odún *Òmìnira* ti *orílè Èdè Nàìjíríà* ?? lónìí ooo. Èmí wa yóò se púpò rè láyé. E jòwó, e má sì gbàgbé láti se *ìwúre* fún orílè èdè *Nàìjíríà* ?? nítorí wí pé *”Ìròrùn igi ni ìròrùn ...
Read More »Awon agba osere apanilerin meji
Read More »Ìyàwó mi dáa tí mo sì le pè ní aya rere sùgbón kìí gbà kí á bá ara wa lò nígbà tí ó ye, lóòtó aní omo okùnrin pèlú obìnrin. E jò ó kí ni mo le se? Mo ti ...
Read More »