Home / Àṣà Oòduà / Awon Oruko Minisita Buhari Lati Enu Awon Omo Naijeria Niyii

Awon Oruko Minisita Buhari Lati Enu Awon Omo Naijeria Niyii

Awon Minisita Buhari: Niwon igba ti awon ara ilu si n reti oruko awon eniyan ti Aare Buhari fe fi je minisita, awon oruko wonyii ni awon ara ilu ni oseese ko jeyo ninu awon oruko minisita ti Buhari ko ni pe gbe jade.

1. Prof. Tam David West
2. Femi Falana (SAN)
3. Lt.-Gen. Abdulrahman Dambazu (rtd)
4. Prince Olagunsoye Oyinlola
5. Wale Edun
6. Abubakar Malami (SAN).
7. Mrs. Ifueko Omoigui-Okaru
8. Chief Bode Mustapha
9. Engineer Segun Oni
10. Dr Kayode Fayemi
11. Dr. Abba Ruma
12. Chief Kanu Agabi
13. Donald Duke
14. Babatunde Raji Fashola
15. Chibuike Rotimi Amaechi
16. Rotimi Akeredolu
17. Rabiu Musa Kwankwanso
18. Festus Odimegwu
19. Engineer Funsho Kupolokun
20. Yinka Folashade Oredola
21. Bisola Adegbenro
22. Isaiah Danjuma (omo TY Danjuma)
23. Dele Momodu
24. Kehinde Lawanson
25. Chief Bayo Ojo (SAN)
26. Pat Utomi
27. Charles Chukwuma Soludo

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Buhari kí Obaseki kú oríire

Buhari kí Obaseki kú oríire Ààrẹ Muhammadu Buhari ti ránṣẹ́ kú orííre sí Godwin Obaseki lẹ́yìn tó jáwé olúborí nínú ìdìbò gómìnà tó wáye lónìí nípìnlẹ̀ Edo. Obaseki tó jẹ́ olùdíje dupò gómìnà lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú PDP ló fi ìdí akẹgbẹ́ rẹ̀ lábẹ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú APC Ize-Iyamu janlẹ̀. Nínú àtẹjáde náà ti Garba Shehu tó jẹ́ olùrànlọ́wọ́ pàtàkì fún Ààrẹ Buhari lórí ìpolongo fọwọ́sí, ló ti dúpẹ́ lọ́wọ́ àwọn elétò ìdìbò fún bi wọ́n ṣe kéde Obaseki bí ẹni to ...