Home / Àṣà Oòduà / IROYIN OWURO ose yii ti jade oooooooo

IROYIN OWURO ose yii ti jade oooooooo

Ese ‘o gbero ni Ikenne
Paradise ni mama wa bayi – Pst Adeboye
Opelope Mama Kapenta nii nba je – Pst Bakare

Okunrin to feran ibalopo pelu
okunrin farahan ni Abeokuta

Oju to maa ti awon ti won nbu
ijoba mi – Rauf Aregbesola

Abike Dabiri fe ki awon
obinrin ti okunrin ba fipa
lopo maa so tenu won sita

Lati odun kewaa gbako, awon agbegbe
kan ko ni ina monamona ni Ibafo
* Lai ni transformer, Liberty Estate tiraka ra opo ina bii ogbon
* Won pa ejo rapata kan nibe

Arepo lo je k’epo won ni Naijiria

Ekun Iyawo gbe asa
ati ede wa laruge
* O ti fe di agbelewo

Emi ko tii ku o.
Mo wa laye,
mo wa laaye
– Alabi Yelo
* O ti di
efangeliisi
bayii

IFOLORUNSHO ALAKIJA: Obinrin to lowo julo ni Naijiria
* Eko pataki ninu itesiwaju ati oriire reg

Awon omobinrin ti ko
m’okunrin s’ojoobi fun
Princess Adediran

Ibo Kogi di yanpon-yanrinbati oloronbo lo lemi kuro l’Eko Akete – Alujo Rasheed

Ilu nla gan-an ni ilu Anifowoshe
Ayipada rere yoo ba ilu Anifowoshe
– Hon. Fatai Anifowoshe

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

seun kuti

Orí kó Seun Kuti yọ kúrò lọ́wọ́ ikú ní yàrá ìgbàlejò US

Mary Fágbohùn Olórin Afrobeat Seun Kuti ti fi ìrírí ibanuje ọkàn rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà han nígbà tí ọta ibọn kan gúnlẹ̀ lójú fèrèsé yàrá igbalejo rẹ̀. O salaye ibapade to ba ni lẹru naa lori oju-iwe Instagram rẹ, o fi fidio ferese ti ọta ibọn naa bajẹ ati iho re han. Seun, ẹni ti o ṣalaye iyalẹnu, beere iwoye ti aabo ni Amẹrika. Ninu fonran naa, Seun Kuti sọ pe oun wa ninu yara igbalejo, ti oun n sinmi, ...