Home / Àṣà Oòduà / Ogundameji: IFA verse for physical & spiritual protection against enemies

Ogundameji: IFA verse for physical & spiritual protection against enemies

Ogundameji is the IFA verse to be recites every day by any person who want to be protected from physical and any spiritual attack.recite this every day.
A Mon anan
A Mon oni
A aa mola
Botunla omo iya e
Bi o suhan bi ko ni suhan
Enikan omon
Awon lo da IFA fun orumila
IFA yi o raga go omo re
Big igun igemon
IFA raga bomi
Ewe oori ni raga boori
IFA raga bomi
Etipa elila ni raga bo ile
IFA raga bomi
Bi adiye ba pamon a raga both
IFA raga bomi
Bi omi NLA se n raga bo yanrin lodo
IFA raga bomi
TRANSLATION
We know yesterday
We know today
We didn’t know tomorrow
The next tomorrow its sibling
Whether it will be pleasant or not
Nobody knows
IFA divination was performed for Orunmila
When IFA will protect his children
Like vulture in the city of Igemon
IFA protect it is the leave with which solid pap
Is wrapped that protect the solid pap
IFA protect me
It is etipa elila leave that protect the soil.
IFA protect me
Whenever a hen hatches chicks
It protect them with its arm
IFA come and protect me
As plenty of water protect sand in the river
IFA protect me against any physical and spiritual attack from enemies ase.
Courtesy Awo Pele Obasa Obanifa Contact +2348166343145 ile ife osun state Nigeria.

About oodua

3 comments

  1. Powerful verse. Ase oo… Amen

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

ifa

Kùtùkùtù Ìrèní Laó He Erè Nígbódù Oòni

Òní laó roko létí opónÒla laó sákà lágbèrùKùtùkùtù ìrèní laó he erè nígbódù oòniKáyáa múlé pontíKámú òdèdè rokàKáfi agbada dínranÀwèje wèmu nípón omodé wòyí lójúÒrìsà lópabuké tánLódákún sábaro nídìíOmo-ojo húnsáré gíríjo-gíríjoOmo-ojo húnsáré gìrìjo-gìrìjoIlé-ifón kògba obàtáláÈlàgboro kògba òrìsàOjúgboro ni tàfínÈlàgboro ni tòrìsàOmi níti ojú-omi rúwáÈròyà wáàponÈròyà wáàmuRúkú-rùkù-rúkú niwón nse lókè ohùnkòErú kùnrin won nííjé bánakúErú bìnrin won nííjé wòrúkúDimúdimù aleìgbòOkùnrin yàkàwú orí ìgbáÌgbá kòwóOkùnrin yàkàwú kòsòkalèÒní laóko igbó olú-kóókó-bojoÒla laóko igbó olú-kóókó-bojoAkogbó olú-kóókó-bojo tánApa ekùn kan mìnììjò-miniijo tínbe lábé ìtíWónní kí ...