Home / Àṣà Oòduà / Onka ede Yoruba 100 – 20,000

Onka ede Yoruba 100 – 20,000

Orisun

 Onka ede Yoruba
100-Ọgọrun
110- Adọfa, àádọ́fà
120- Ọgọfa
130- Aadoje
140- Ogoje
150- Adọjọ, àádọ́jọ
160-Ọgọjọ
170-Adọsan, àádọ́sán
180- Ọgọsan
190-Mẹwadinigba
200-Igba
E tesiwaju ni isale lẹhin iwe Bireki yii (Continue after the page break bellow)

About BalogunAdesina

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo