Abi foto Buroda Alabi Pasuma ko ni mo n wo yii ni? Ko ma si eni ti Olorun ko le fi owo to lokan sa o. Burudo Pasuma, Orobokibo Creator, Oga Nla 1, Ijaya of Fuji, Oluwa yoo ma so agbara yin dotun oo.

Abi foto Buroda Alabi Pasuma ko ni mo n wo yii ni? Ko ma si eni ti Olorun ko le fi owo to lokan sa o. Burudo Pasuma, Orobokibo Creator, Oga Nla 1, Ijaya of Fuji, Oluwa yoo ma so agbara yin dotun oo.
Kò sí ohun ẹlẹ́mìí kankan láyé awo ilé Ayé ni ọ̀run àkọ́kọ́, ohun tí ó so kàrà tí kò sọ̀kalẹ̀, awo òde Ọ̀run ni ó ń pè é, gbogbo rẹ̀ jẹ́ òfìfo lásán, òfo pónbele, láìní ìpìlẹ̀, láìní ẹ̀dá kankan, Awo àárín gbùn-gbùn òde ni ó wí i, A dífá fún Ayé àti fún Ọ̀run, nínú ìkarawun ìgbín méjì tí ó ṣófo, kò sí ẹyẹ, kò sí ẹ̀mí tí ń gbé inú wọn, ìpìlẹ̀ kò tí ì sí, afẹ́fẹ́ kò ...