Home / Àṣà Oòduà / Nìjíríà ìgbà wo ni a ó gba òmínira.

Nìjíríà ìgbà wo ni a ó gba òmínira.

Nìjíríà ńlé sunkún
Àwon èèyàn ibè ò ye é rérìn-ín òfò
Èrín òfò tí won rò pé ti ìdùnú ní se

Nìjíríà ìlú tí òmínira rè ti di omi ìnirà
Atún ti wálé
Ojó wo ni àwa náà yóò gba ife gbogbo àgbáyé
Ó mà se o!

Argentina tún ko bò wá láàná, won tún lé wa léré wálé láti odún 1995 ni wón kúkú ti ń fó wa lénu.

Ikò super Eagles ti láwon ò super mó oo A ti dágbére fún won ní Russia

Nìjíríà ìlú olómìnira.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo