Home / Àṣà Oòduà / Tánkà tí Ó gbiná ní ànà tí Ó sì pa òpò èèyàn.

Tánkà tí Ó gbiná ní ànà tí Ó sì pa òpò èèyàn.

Ní déédé agogo márùn-ún ìròlé àná ni ìjàmbá ńlá tí Ó tún jé mánigbàgbé fún orílè èdè Nìjíríà selè, nígbà tí Tánkà ńlá kan gbiná ní ojú pópó ònà tí ó wà láàrin ìlú Èkó si Ìbàdàn.

Òpò àwon èèyàn ni ókú tí àwon kan sì fi ara pa, ti Òpò okò sì sègbé.
Ó mà se o àfi kí olórun gbà wá ní orílè èdè yí.

Kí elédùmarè té àwon tí Óní kú sí aféfé rere.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?