Home / Àṣà Oòduà / Sayewo Omo Ita, Jaguda Ti Buhari Fi Se Oludamora Nipa Oro To N Lo Nile Igbimo Asofin

Sayewo Omo Ita, Jaguda Ti Buhari Fi Se Oludamora Nipa Oro To N Lo Nile Igbimo Asofin


Honorebu Suleiman A. Kawu ni yii, okan ninu awon omo ile igbimo asofin ti n fo iganna nigba rogbodiyan to waye nile igbimo asofin ni akoko ti Goodluck Jonathan wa lori oye gege bi Aare ile Nigeria olominira.

Maanu yii kan naa wa lara awon ti Aare Muhammadu Buhari ti yan bayii gege bi oludamoran nipa awon oro to n lo nile igbimo asoju sofin ile Nigeria.

Pelu bi oko Aisha se n pariwo wi pe awon eniyan gidi, omoluabi oloselu ati olooto ni awon eniyan ti oun fe ninu isejoba oun, nje awa le pe eniyan ti n fo iganna gege bi omoluabi alaponle bi?

 

Orisun

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

“Ta Ní Ó Wà Kí Ayé Tó Wà? Ìtàn Àkọ́kọ́ Ìṣẹ̀dá Gẹ́gẹ́ Bí Ifá Ṣe Sọ Ó.”

Kò sí ohun ẹlẹ́mìí kankan láyé awo ilé Ayé ni ọ̀run àkọ́kọ́, ohun tí ó so kàrà tí kò sọ̀kalẹ̀, awo òde Ọ̀run ni ó ń pè é, gbogbo rẹ̀ jẹ́ òfìfo lásán, òfo pónbele, láìní ìpìlẹ̀, láìní ẹ̀dá kankan, Awo àárín gbùn-gbùn òde ni ó wí i, A dífá fún Ayé àti fún Ọ̀run, nínú ìkarawun ìgbín méjì tí ó ṣófo, kò sí ẹyẹ, kò sí ẹ̀mí tí ń gbé inú wọn, ìpìlẹ̀ kò tí ì sí, afẹ́fẹ́ kò ...