Home / Author Archives: Awo

Author Archives: Awo

ERÍWO YÀ! ERÍWO YÀ!! ERÍWO YÀ!!!

Gbogbo ẹ̀yin Babaláwo àti Oníṣẹ̀ṣe lápapọ̀; Ojú rẹ rèé o : Babaláwo Babájídé Ọ̀ṣúnníyì (Olúwo Jọ̀gbọ̀dọ́ Ọ̀rúnmìlà). Ní òní yìí ni ìgbẹ́jọ́ ẹ̀sùn oyún síṣẹ́ fún ọ̀dọ́mọbìnrin tó ṣẹ̀ṣẹ̀ padà sí ìdí Ifá / Ìṣẹ̀ṣe (lẹ́yìn ikú Baba rẹ ní ...

Read More »

OAU se ìràntí àwon akoni tí won pàdánù èmí won sí owó àwon omo egbé òkúnkùn ní ogún odún séyìn.

OAU se ìràntí àwon akoni tí won pàdánù èmí won sí owó àwon omo egbé òkúnkùn ní ogún odún séyìn. Àwon alámòójútó àti akékòó ilé-èkó gíga Obafemi Awolowo University ti ilé- ife, máa péjo sí gbàgede Amphitheater tí ilé èkó ...

Read More »

Èèmò lukutu pébé.

Òdókùnrín tí ó n fi èro ayélujára gbáni, tí ó n se Yahoo yahoo, ni owó ti tè níbi tí ó ti n gbé òkú arábìnrin tí ó pa sí hòtélì lo. Owó sìkún àwon agbófinró ti te odókùnrin tí ...

Read More »

Egbé agbá bóòlú fún orílè èdè Nìjíríà àti ti Cameroon: Ìghàló gégé bíi òdómokùnrin tí ó gbégbá orókè nínú eré bóòlù náà.

Egbé agbá bóòlú fún orílè èdè Nìjíríà àti ti Cameroon: Ìghàló gégé bíi òdómokùnrin tí ó gbégbá orókè nínú eré bóòlù náà. Omo egbé agbá bóòlù fún orílè èdè Nìjíríà tí na àwon omo egbé agbá bóòlú Cameroon ní méta ...

Read More »

Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó.

Arewà obìnrin kan ni ó gbé o n je omo (oyàn) rè han nínú àwòrán òun àti oko àfésónà kí won tó se ìgbéyàwó. Arábìnrin tí ó jé omo orílè èdè Nìjíríà ní ó fi orí oyàn hàn níbi àwòrán ...

Read More »

Ìyàlénu àti ohun tó mórí wú lójé nígbá tí tè’gbón tà’búrò yí dì mó ara won.

Ìyàlénu àti ohun tó mórí wú lójé nígbá tí tè’gbón tà’búrò yí dì mó ara won. Àwon arewà omodé méjì yí, ni won ti kí a mo rírì ìfé tí èjè máa ni sí ara won. Omokùnrin kan láti orílè ...

Read More »

Arábìnrin tí ó n se ayédèrú mílìkì olópe.

Arábìnrin tí ó n se ayédèrú mílìkì olópe. Owó sìnkú àwon agbófinró ti orílè èdè Nìjíríà ti te Arábìnrin tí ó n se ayédèrú mílìkì olópe ní ònà gbòòrò. Nígbà tí ó ní irú opolo láti se èyí, kílódé tí ...

Read More »

Ogbè Até

Owó òtún mi ni mo fi n gba ire Adífáfún Sará Sará N’ílé olódùmarè la gbé n báwon Lóri orí eni òré òhun tìmùtìmù rere Àtélewó mi òsì Ni mo fi n gba ìfà Adífáfún Sèbí Sèbí N’ílé olódùmare ni ...

Read More »

Àwon tí ó n gbélè sunkún síta fún ìrànlówó nígbà tí àwon adigunjalè jàwón lólè ní Bayelsa.

Àwon olùgbé Opolo ní Yenagoa ìpínlè Bayelsa ni ìbèrùbojo ti gba okàn won léyìn tí àwon adigunjalè jà won lólè tán. Gégé bí ìròyìn se so, àwon olè yí kojá ogbòn tí won sì gbé àwon ohun ìjà olóró lówó ...

Read More »

Mi ò le fé okùnrin tí kò bá le bámi sùn fún wákàtí méjìlá sí méèdógún.

Mi ò le fé okùnrin tí kò bá le bámi sùn fún wákàtí méjìlá sí méèdógún. Arábìnrin kan tí a kò fi taratara mo orúko rè súgbón tí kò le jú omo odún méèdógún sí ogbòn kan ni ó so ...

Read More »