Home / Author Archives: Awo (page 15)

Author Archives: Awo

Odun odun kan ko dun dun

Ko dun bi odun yi ri Odun ti o dun ni odun ominira1960 Odun n dun ni dundun n dun Orile-ede ti n San fun wara ati oyin Orile-ede abinibi Nigeria Adugbo ti n toro omo ale ni ke ti ...

Read More »

ỌJỌ́ NÁÀ RÈÉ BÍ ÀNÁ

  Ọjọ́ náà rèé bí àná. Bí eré bí àwàdà; Kánmọ́kánmọ́ l’ọjọ́ ń șí lọ bí ẹyẹ. Ọjọ́ náà rèé bí àná; Tá a bẹ̀rẹ̀ ìgbésẹ̀ ìrìn-àjò ọ̀hún. Òjòó rọ̀ wọ̀wọ̀. Afẹ́fẹ́ fẹ́ ilẹ́lẹ́-ilẹ́lẹ́. Ẹ̀fúùfùlẹ̀lẹ̀ẹ́ m’igi oko dìgbàdìgbà. Ojúu sánmọ̀ọ́ ...

Read More »

Àwon Akékòó Ogbà Fémi jà fún ètó won

Bí a bá pè é ní ìjà láàrin akékòó eka èkó gèésì (Department of English ) àti ti àwon eka èkó nípa òfin (faculty of law) ti ilé-èkó gíga ifáfitì ti Obafemi Awolowo university wo ìyá ìjàkadì Látàrí wípé àwon ...

Read More »

ITAN ORANMIYAN BABA NLA GBOGBO YORUBA AWON EYA TO WA NILE TABI ORILEDE ODUA

ITAN ORANMIYAN BABA NLA GBOGBO YORUBA AWON EYA TO WA NILE TABI ORILEDE ODUA Loni opo enia mo nro pe gbogbo awa ti awa ni ipinle mefa yi Oyo, Osun, Ogun, Ondo, Ekiti, Eko pelu ipinle Kwara to nka ara ...

Read More »

A kú àmójúbà *Osù Agemo (July)

Bí a se wonú osù yìí, a kò níí se gégé ibi, ibi kò níí se gégé wa. Ikú iwájú tó ñ pa wón, odò èyìn tó ñ gbé won ón lo, Oba Adédàá kò níí ka ìpín òkóòkan wa ...

Read More »

ÌȘẸLẸ̀ INÁ NÍ BÁGÀ

Hàáààà!!! Iná ooooooo. Iná pupa bẹ́lẹ́ńjẹ́. Bẹ́lẹ́ńjẹ́ bẹ̀lẹ̀ǹjẹ̀ bẹ́lẹ́ńjẹ́. Bẹ́lẹ́ńjẹ́ pupa arańta. Iná gorí òrùlé tán; Ó wá fẹjú kẹkẹẹkẹ. Ìpínlẹ̀ Èkó gb’àlejò iná ńlá. L’ágbègbè Òjòdú Bágà. Ó kọjá ohun a le máa f’ẹnu sọ. Iná ṣe bẹ́ẹ̀, ó ...

Read More »

Ó mà se ooo

Àfi kí olórun, elédùmarè gbà wá lówó ikú òjijì ní orílè èdè Nìjíríà. Kí tún ní eléyìí báyìí olúwa gbà wà, e wo òkú òpò nílè bí won se jó ná tán à kí olórun gbà wá wo.

Read More »

Tánkà tí Ó gbiná ní ànà tí Ó sì pa òpò èèyàn.

Ní déédé agogo márùn-ún ìròlé àná ni ìjàmbá ńlá tí Ó tún jé mánigbàgbé fún orílè èdè Nìjíríà selè, nígbà tí Tánkà ńlá kan gbiná ní ojú pópó ònà tí ó wà láàrin ìlú Èkó si Ìbàdàn. Òpò àwon èèyàn ...

Read More »

Nìjíríà ìgbà wo ni a ó gba òmínira.

Nìjíríà ńlé sunkún Àwon èèyàn ibè ò ye é rérìn-ín òfò Èrín òfò tí won rò pé ti ìdùnú ní se Nìjíríà ìlú tí òmínira rè ti di omi ìnirà Atún ti wálé Ojó wo ni àwa náà yóò gba ...

Read More »

A DÚPẸ́ OOO GBOGBO ILẸ̀ WA TI DI IBOJÌ

A dúpẹ́ o Ikú ti di tiwa A dúpẹ́ o Àwọn èèyàn wa ò figi da mààlúù mọ́ AK 47 ni wọ́n ń lò A dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run Iṣẹ́ darandaran ti di iṣẹ́ dánràndáràn Èdùmàrè a dúpẹ́ o Ẹ dúró ...

Read More »